November 1 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ǹjẹ́ Ó Tọ́ Ká Máa Bi Ọlọ́run Ní Ìbéèrè? Ìbéèrè Kìíní: Ìwọ Ọlọ́run, Kí Nìdí Tó O Fi Dá Mi Sáyé? Ìbéèrè Kejì: Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ sí Mi Nígbà Tí Mo Bá Kú? Ìbéèrè Kẹta: Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Jẹ́ Kí Ìyà Máa Jẹ Mí? Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà Ǹjẹ́ O Mọ̀? Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ǹjẹ́ Ọlọ́run Yóò Fún Wa Ní Ìjọba Kan Tó Máa Ṣàkóso Gbogbo Ayé? Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀ Ohun Tí Ẹ Lè Ṣe Nípa Gbèsè Sún Mọ́ Ọlọ́run ‘Kí Ni Ohun Tí Jèhófà Ń Béèrè Láti Ọ̀dọ̀ Rẹ?’ Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . Ṣé Ẹni Tó Bá Lóun Ní Ìgbàgbọ́ Kàn Ń Tan Ara Rẹ̀ Jẹ Ni? Ẹ̀kọ́ Bíbélì Bí Ìgbésí Ayé Ṣe Rí Lákòókò Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì—Olùṣọ́ Àgùntàn Ilé Ẹjọ́ Ilẹ̀ Yúróòpù Gbèjà Ẹ̀tọ́ Ẹni Tí Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ̀ Kò Jẹ́ Kó Ṣiṣẹ́ Ológun Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá?