July 1 Ṣọ́ọ̀ṣì kan Tí Ìyapa Wà—Báwo Ni Ó ṣe Burú Tó? Ṣọ́ọ̀ṣì kan Tí Ìyapa Wà—Ó Ha Lè Làájá Bí? Lórí Tábìlì Wo Ni Ìwọ Ti Ń Jẹun? Kí Ni Ó Ti Ṣẹlẹ̀ Sí Ọlá-àṣẹ? Ojú-Ìwòye Kristian Nípa Ọlá-Àṣẹ Fífayọ̀ Tẹríba Fún Ọlá-Àṣẹ “Èmi Ti Pa Ìgbàgbọ́ Mọ́” Ìpàdé Ọdọọdún Wọ́n Darapọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Àwọn Ará tí Wọ́n Sopọ̀ṣọ̀kan