November 1 Àwọn Èèyàn Ń Wá Aṣáájú Rere Ta Ló Dáńgájíá Láti Jẹ́ Aṣáájú Lóde Òní? Aláyọ̀ ni Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà Wọ́n Ń ṣe Inúnibíni Sí Wa Síbẹ̀ À Ń láyọ̀ Ǹjẹ́ O Mọ̀ Pé Ayọ̀ Wà Nínú Ṣíṣètọrẹ? Ìṣàkóso Ọlọ́run Làwá Fara Mọ́ Bí Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ Jèhófà Ṣe Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé Ǹjẹ́ Ìgbà Kan Tiẹ̀ Máa Wà Tá A Máa Ní Ààbò Tòótọ́? Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Bẹ̀ Ọ́ Wò?