September 1 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ṣé Ọlọ́run Ṣèlérí fún Ẹ Pé Wàá Dọlọ́rọ̀? Ọrọ̀ Tó Ń Ti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wá Ṣé Ipò Òṣì Túmọ̀ Sí Pé Inú Ọlọ́run Ò Dùn sí Wa? Ṣé Owó Ni Orísun Ayọ̀ Tòótọ́? Ó Láyọ̀ Ó sì Nírètí Bí Kò Tiẹ̀ Lówó Lọ́wọ́ Ṣẹ́ni Gidi ni Ádámù àti Éfà? Wọ́n Ṣàwárí Bíbélì Tó Ṣeyebíye Ǹjẹ́ O Mọ̀? Onídàájọ́ Tó Máa Ń Ṣohun Tó Tọ́ Nígbà Gbogbo Táwọn Èèyàn Bá Ṣe Ohun Tó Dùn Ẹ́ Ìyanu Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Pẹ́ńtíkọ́sì! Àwọn Ohun Ṣíṣeyebíye Tó Wà Ní Adágún Títóbi Jù Lọ Ní Amẹ́ríkà Àárín Báwo Ni Jésù Àti Bàbá Rẹ̀ Ṣe Jẹ́ Ọ̀kan? Béèyàn Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí Lẹ́nu Iṣẹ́ Míṣọ́nnárì Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá?