Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September 1, 2009
Ṣé Ọlọ́run Ṣèlérí Pé Wàá Dọlọ́rọ̀?
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Ṣé Ọlọ́run Ṣèlérí fún Ẹ Pé Wàá Dọlọ́rọ̀?
4 Ọrọ̀ Tó Ń Ti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wá
8 Ṣé Ipò Òṣì Túmọ̀ Sí Pé Inú Ọlọ́run Ò Dùn sí Wa?
9 Ṣé Owó Ni Orísun Ayọ̀ Tòótọ́?
10 Lẹ́tà Láti Orílẹ̀-Èdè Bòlífíà
16 Wọ́n Ṣàwárí Bíbélì Tó Ṣeyebíye
18 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
19 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Onídàájọ́ Tó Máa Ń Ṣohun Tó Tọ́ Nígbà Gbogbo
24 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Ìyanu Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Pẹ́ńtíkọ́sì!
25 Àwọn Ohun Ṣíṣeyebíye Tó Wà ní Adágún Títóbi Jù Lọ ní Amẹ́ríkà Àárín
29 Béèyàn Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí Lẹ́nu Iṣẹ́ Míṣọ́nnárì
OJÚ ÌWÉ 12
Táwọn Èèyàn Bá Ṣe Ohun Tó Dùn Ẹ́
OJÚ ÌWÉ 20