May 8 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ṣé Ogun Ló Ń Gbé Lárugẹ Ni Àbí Àlàáfíà? Ọ̀rúndún Tó Kún Fún Ìwà Ipá Àlàáfíà Kárí Ayé Kì í Ṣe Àlá Tí Kò Lè Ṣẹ o! Kí Ló Dé Tí Àjọgbé Èmi àti Alábàágbé Mi Fi Nira? Ohun Kan Tó Jẹ́ Àdámọ́ Gbogbo Èèyàn Kí Ló Dé Táwọn Èèyàn Ń Fi Àwọn Ẹ̀sìn Tó Ti Wà Látayébáyé Sílẹ̀? Ṣé “Àdábọwọ́ Ìsìn” Ló Máa Yanjú Ọ̀rọ̀ Náà? Ọ̀nà Tó Dára Jù Lọ Láti Rí Ìtẹ́lọ́rùn Tẹ̀mí A Bù Kún Ìdánúṣe Tó Lò Oúnjẹ Aṣaralóore Ń Bẹ Níkàáwọ́ Rẹ Ńjẹ́ Ọlọ́run Fọwọ́ Sí Ogun Jíjà? Ìtùnú fún Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Ẹ̀jẹ̀ Ríru—Bá A Ṣe Lè Dènà Rẹ̀ àti Bá A Ṣe Lè Kápá Rẹ̀ “Akérékorò Ni Ìwé Náà”