July Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ṣé Ìjì Tó Ń Jà Yìí Ò Ní Í Gbé Ìgbéyàwó Lọ? Béèyàn Ṣe Lè Láyọ̀ Nínú Ìgbéyàwó Kí Nìdí Tó Fi Pọn Dandan Fún Mi Láti Máa Kàwé? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣọ́wó Ná? Báwo Ni Kí N Ṣe Lo Ìgbésí Ayé Mi? Ǹjẹ́ O Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Hẹ́gẹhẹ̀gẹ Ọjọ́ Ogbó? Kí Nìdí Tá A Fi Ń Darúgbó? Báwo Lo Ṣe Máa Pẹ́ Tó Láyé? Àǹfààní Wo Ló Wà Nínú Jíjẹ́ Ẹlẹ́mìí Àlàáfíà? Kí Ni Ẹ̀ṣẹ̀ Ìpilẹ̀ṣẹ̀? Kí Ni Ẹ̀mí Mímọ́ Ọlọ́run? Ṣé Ó Ṣeé Ṣe Kí Ayọ̀ Jọba Nínú Ìdílé?