Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè (ll) Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú APÁ 1 Báwo La Ṣe Lè Tẹ́tí sí Ọlọ́run? APÁ 2 Ta Ni Ọlọ́run Tòótọ́? APÁ 3 Báwo Ni Ìgbésí Ayé Ṣe Rí Nínú Ọgbà Édẹ́nì? APÁ 4 Kí Ló Ṣẹlẹ̀ Lẹ́yìn Tí Wọ́n Tẹ́tí sí Sátánì? APÁ 5 Nígbà Ìkún Omi, Àwọn Wo Ló Tẹ́tí sí Ọlọ́run? Àwọn Wo Ni Kò Tẹ́tí sí I? APÁ 6 Kí Ni Ìkún Omi Náà Kọ́ Wa? APÁ 7 Ta Ni Jésù? APÁ 8 Kí Ni Ikú Jésù Mú Kó Ṣeé Ṣe fún Ọ? APÁ 9 Ìgbà Wo Ni Ayé Máa Di Párádísè? APÁ 10 Àwọn Ìbùkún Wo Ni Àwọn Tó Bá Tẹ́tí sí Ọlọ́run Máa Rí Gbà? APÁ 11 Ṣé Jèhófà Máa Ń Tẹ́tí Gbọ́ Wa? APÁ 12 Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Ní Ayọ̀? APÁ 13 Kí La Lè Ṣe Láti Mú Inú Ọlọ́run Dùn? APÁ 14 Báwo Lo Ṣe Lè Fi Hàn Pé O Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà?