August Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, August 2017 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò August 7-13 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 28-31 Jèhófà San Ìlú Abọ̀rìṣà Kan Lẹ́san MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Ànímọ́ Kristẹni Tó Yẹ Kó O Ní—Ìrẹ̀lẹ̀ August 14-20 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 32-34 Iṣẹ́ Ńlá Ni Iṣẹ́ Olùṣọ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Ànímọ́ Kristẹni Tó Yẹ Kó O Ní—Ìgboyà August 21-27 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 35-38 Gọ́ọ̀gù Ti Ilẹ̀ Mágọ́gù Máa Tó Pa Run MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Ànímọ́ Kristẹni Tó Yẹ Kó O Ní—Ìgbàgbọ́ August 28–September 3 TREASURES FROM GOD’S WORD | ÌSÍKÍẸ́LÌ 39-41 Bí Ìran Tẹ́ńpìlì Tí Ìsíkíẹ́lì Rí Ṣe Kàn Ọ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ìgbà Wo Ni Mo Tún Lè Ṣe Olùrànlọ́wọ́ Aṣáájú-Ọ̀nà?