TREASURES FROM GOD’S WORD | ÌSÍKÍẸ́LÌ 39-41
Bí Ìran Tẹ́ńpìlì Tí Ìsíkíẹ́lì Rí Ṣe Kàn Ọ́
Àwọn ìyẹ̀wù tàbí yàrá ẹ̀ṣọ́ àti àwọn òpó gíga ń jẹ́ ká mọ̀ pé Jèhófà ní àwọn ìlànà tó ga fún ìjọsìn rẹ̀ mímọ́
Bi ara rẹ pé, ‘Àwọn nǹkan wo ni mo lè ṣe tó máa fi hàn pé mo fara mọ́ àwọn ìlànà Jèhófà?’