ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 September ojú ìwé 3
  • Ìjọsìn Mímọ́ Pa Dà Bọ̀ Sípò!

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìjọsìn Mímọ́ Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Òfin Tẹ́ńpìlì Náà Nìyí”
    Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • “Ṣàlàyé Bí Tẹ́ńpìlì Náà Ṣe Rí”
    Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • “Fi Ọkàn-àyà Rẹ Sí” Tẹ́ńpìlì Ọlọ́run!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
  • Bí Ìran Tẹ́ńpìlì Tí Ìsíkíẹ́lì Rí Ṣe Kàn Ọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 September ojú ìwé 3

TREASURES FROM GOD’S WORD | ÌSÍKÍẸ́LÌ 42-45

Ìjọsìn Mímọ́ Pa Dà Bọ̀ Sípò!

Jèhófà fi ìran tẹ́ńpìlì han Ìsíkíẹ́lì, kó bàa lè mú kí àwọn Júù tó wà nígbèkùn ronú pìwà dà, kó sì fi wọ́n lọ́kàn balẹ̀ pé ìjọsìn mímọ́ máa pa dà bọ̀ sípò. Bákan náà, ó tún ń rán wọn létí pé àwọn ìlànà Jèhófà fún ìjọsìn mímọ́ ga gan-an.

Àlùfáà kan ń kọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní Òfin, alàgbà kan sì ń fi Bíbélì kọ́ àwọn ará ní ìpàdé ìjọ

• Àwọn àlùfáà máa kọ́ àwọn èèyàn náà ní àwọn ìlànà Jèhófà

44:23

Sọ díẹ̀ lára àwọn ọ̀nà tí ẹrú olóòótọ́ àti olóye gbà kọ́ wa ní ìyàtọ̀ láàárín ohun tí kò mọ́ àti ohun tí ó mọ́. (kr 110-117)

• Àwọn èèyàn náà máa fọwọ́ sowọ́ pọ̀ pẹ̀lú àwọn tó ń mú ipò iwájú

45:16

Kí ni díẹ̀ lára àwọn ọ̀nà tá a lè gbà fi hàn pé à ń fọwọ́ sowọ́ pọ̀ pẹ̀lú àwọn alàgbà?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́