September Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé September 2017 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò September 4-10 TREASURES FROM GOD’S WORD | ÌSÍKÍẸ́LÌ 42-45 Ìjọsìn Mímọ́ Pa Dà Bọ̀ Sípò! MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Kí Nìdí Tó O Fi Mọyì Ìjọsìn Mímọ́? September 11-17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 46-48 Ohun Tí Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Máa Gbádùn Tí Wọ́n Bá Kúrò Nígbèkùn September 18-24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 1-3 Jèhófà Máa San Wá Lẹ́san Tá A Bá Jẹ́ Adúróṣinṣin sí I MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Adúróṣinṣin Nígbà Ìdẹwò MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Adúróṣinṣin Nígbà Tí Wọ́n Bá Yọ Mọ̀lẹ́bí Rẹ Kan Lẹ́gbẹ́ September 25–October 1 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 4-6 Ṣé Ò Ń Sin Jèhófà Láìyẹsẹ̀? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Kọ́ Wọn Láti Máa Sin Jèhófà Láìyẹsẹ̀