MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Jẹ́ Adúróṣinṣin Nígbà Ìdẹwò
Wo fídíò náà, Jẹ́ Adúróṣinṣin Bíi Jésù—Nígbà Ìdẹwò, lẹ́yìn náà, dáhùn àwọn ìbéèrè yìí:
Ìdẹwò wo ni Ṣẹ́gun dojú kọ tó lè mú kó jẹ́ aláìdúróṣinṣin?
Kí ló ran Sẹ́gun lọ́wọ́ tó fi jẹ́ adúróṣinṣin?
Báwo ni ìdúróṣinṣin rẹ̀ ṣe fi ìyìn fún Jèhófà?