ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 1-3
Jèhófà Máa San Wá Lẹ́san Tá A Bá Jẹ́ Adúróṣinṣin sí I
Ìtàn àwọn Hébérù mẹ́ta yẹn ń fún wa níṣìírí láti jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà
Kí ni àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí fi hàn pé a gbọ́dọ̀ máa ṣe tá a bá fẹ́ jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà?