September 18-24
DÁNÍẸ́LÌ 1-3
Orin 131 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Máa San Wá Lẹ́san Tá A Bá Jẹ́ Adúróṣinṣin sí I”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Dáníẹ́lì.]
Da 3:16-20—Àwọn ọ̀rẹ́ Dáníẹ́lì jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà nígbà tí wọ́n kojú àdánwò ńlá (w15 7/15 25 ¶15-16)
Da 3:26-29—Ìdúróṣinṣin wọn fi ìyìn fún Jèhófà, Jèhófà sì san wọ́n lẹ́san (w13 1/15 10 ¶13)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Da 1:5, 8—Kí nìdí tí Dáníẹ́lì àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta fi gbà pé táwọn bá jẹ oúnjẹ tí ọba gbé kalẹ̀, ó máa sọ àwọn di ẹlẹ́gbin? (it-2 382)
Da 2:44—Kí nìdí tí Ìjọba Ọlọ́run fi máa fòpin sí àwọn ìjọba ayé tí ère yẹn ṣàpẹẹrẹ? (w12 6/15 17, àpótí; w01 10/15 6 ¶4)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Da 2:31-43
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 40:22—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ro 15:4—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni—Fún un ní káàdì ìkànnì JW.ORG.
Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w17.02 29-30—Àkòrí: Ṣé Jèhófà Ti Kọ́kọ́ Máa Ń Díwọ̀n Ohun Tá A Lè Mú Mọ́ra Kó Tó Wá Pinnu Irú Àdánwò Tó Máa Jẹ́ Kó Dé Bá Wa?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jẹ́ Adúróṣinṣin Nígbà Ìdẹwò”: (8 min.) Ìjíròrò.
“Jẹ́ Adúróṣinṣin Nígbà Tí Wọ́n Bá Yọ Mọ̀lẹ́bí Rẹ Kan Lẹ́gbẹ́”: (7 min.) Ìjíròrò.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr “Apá 6—Ṣíṣètìlẹyìn Fún Iṣẹ́ Ìjọba Ọlọ́run—À Ń Kọ́ Ibi Ìjọsìn, A sì Ń Ṣèrànwọ́ Nígbà Àjálù,” orí 18 ¶1-8
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 101 àti Àdúrà