MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Jẹ́ Adúróṣinṣin Nígbà Tí Wọ́n Bá Yọ Mọ̀lẹ́bí Rẹ Kan Lẹ́gbẹ́
Wo fídíò náà Máa Fi Ìdúróṣinṣin Ti Àwọn Ìdájọ́ Jèhófà Lẹ́yìn—Má Ṣe Bá Àwọn Oníwà Àìtọ́ Tí Kò Ronú Pìwà Dà Kẹ́gbẹ́, lẹ́yìn náà, dáhùn àwọn ìbéèrè yìí:
Kí ló fẹ́ sọ àwọn òbí Ṣadé di aláìdúróṣinṣin?
Kí ló ràn wọ́n lọ́wọ́ tí wọ́n fi jẹ́ adúróṣinṣin?
Torí pé wọ́n jẹ́ adúróṣinṣin, àǹfààní wo ni ìyẹn ṣe fún Ṣadé?