ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 September ojú ìwé 6
  • September 25–October 1

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • September 25–October 1
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 September ojú ìwé 6

September 25–October 1

DÁNÍẸ́LÌ 4-6

  • Orin 67 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ṣé Ò Ń Sin Jèhófà Láìyẹsẹ̀?”: (10 min.)

    • Da 6:7-10​—Dáníẹ́lì fi ẹ̀mí ara rẹ̀ wewu kó lè máa sin Jèhófà láìyẹsẹ̀ (w10 11/15 6 ¶16; w06 11/1 24 ¶12)

    • Da 6:16, 20​—Ọba Dáríúsì rí i pé Dáníẹ́lì ní àjọṣe tímọ́tímọ́ pẹ̀lú Jèhófà (w03 9/15 15 ¶2)

    • Da 6:22, 23​—Jèhófà bù kún Dáníẹ́lì torí pé ó ń sìn ín láìyẹsẹ̀ (w10 2/15 18 ¶15)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Da 4:10, 11, 20-22​—Kí ni arabaríbí igi inú àlá Nebukadinésárì dúró fún? (w07 9/1 18 ¶5)

    • Da 5:17, 29​—Kí nìdí tí Dáníẹ́lì kò fi kọ́kọ́ gba ẹ̀bùn tí Ọba Bẹliṣásárì fún un, àmọ́ tó wá gbà á nígbà tó yá? (w88 10/1 30 ¶3-5; dp 109 ¶22)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Da 4:29-37

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) inv

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) inv​—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé ìkésíni sí àwọn ìpàdé. Ṣe ìpadàbẹ̀wò.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 120 ¶16​—Fún akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní ìṣírí pé kó jẹ́ adúróṣinṣin kódà tí àwọn ará ilé rẹ̀ bá ń ṣe inúnibíni sí i.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 139

  • “Kọ́ Wọn Láti Máa Sin Jèhófà Láìyẹsẹ̀”: (15 min.) Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò bí akéde kan tó ní ìrírí dáadáa ṣe ń ṣiṣẹ́ lóde ẹ̀rí pẹ̀lú ẹnì kan tó ṣẹ̀ṣẹ̀ di akéde.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 18 ¶9-20, àpótí “Kí Là Ń Lo Àwọn Ọrẹ Wa Fún?,” àpótí tó wà fún àtúnyẹ̀wò “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 73 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́