September 11-17
ÌSÍKÍẸ́LÌ 46-48
Orin 134 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ohun Tí Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Máa Gbádùn Tí Wọ́n Bá Kúrò Nígbèkùn”: (10 min.)
Isk 47:1, 7-12—Ilẹ̀ wọn máa di ilẹ̀ ọlọ́ràá (w99 3/1 10 ¶11-12)
Isk 47:13, 14—Ìdílé kọ̀ọ̀kan ló máa gba ogún (w99 3/1 10 ¶10)
Isk 48:9, 10—Kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ sí í pín ilẹ̀ fún àwọn èèyàn, wọ́n á kọ́kọ́ ya apá ibi tó dára gan-an sọ́tọ̀ gẹ́gẹ́ bí “ọrẹ” fún Jèhófà
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Isk 47:1, 8; 48:30, 32-34—Kí nìdí tí àwọn Júù tí wọ́n kó nígbèkùn yẹn kò fi retí pé kí gbogbo nǹkan tí Ìsíkíẹ́lì rí nínú ìràn tẹ́ńpìlì yẹn rí bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́? (w99 3/1 11 ¶14)
Isk 47:6—Kí ni ìdí tí ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí fi pe Ìsíkíẹ́lì ní “ọmọ ènìyàn”? (it-2 1001)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 48:13-22
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn wp17.5—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) wp17.5—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé ìròyìn yìí. Ṣe ìpadàbẹ̀wò, kó o sì fi ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tá a fi ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì hàn án.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 34 ¶17—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Song 28
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.) Tàbí kẹ́ ẹ jíròrò ohun tẹ́ ẹ rí kọ́ nínú Ìwé Ọdọọdún. (yb17 64-65)
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù September.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 17 ¶19-20, àpótí “Àwọn Ilé Ẹ̀kọ́ Tó Ń Dá Àwọn Òjíṣẹ́ Ìjọba Ọlọ́run Lẹ́kọ̀ọ́,” àpótí tó wà fún àtúnyẹ̀wò “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 11 àti Àdúrà