January Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, January-February 2023 January 2-8 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀? January 9-15 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Máa Fi Ọjọ́ Jèhófà Sọ́kàn January 16-22 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Òótọ́ Làwọn Ìtàn Bíbélì, Kì Í Ṣe Àròsọ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Tó O Ní Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Túbọ̀ Lágbára January 23-29 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Kí Ni Àdúrà Mi Ń Sọ Nípa Irú Ẹni Tí Mo Jẹ́? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Múra Sílẹ̀ Nísinsìnyí fún Ìtọ́jú Pàjáwìrì January 30–February 5 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Kó O Lè Ṣàṣeyọrí Lẹ́nu Iṣẹ́ Tó Le Gan-an MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jèhófà Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Lákòókò Ìṣòro February 6-12 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jẹ́ Kó Máa Wù Ẹ́ Láti Ṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Sapá Láti Mọ Èrò Ọlọ́run MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Nǹkan Wo Lo Lè Fi Ṣe Àfojúsùn Rẹ Lásìkò Ìrántí Ikú Kristi? February 13-19 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN A Máa Ṣàṣeyọrí Tá A Bá Ń Tẹ̀ Lé Ìlànà Jèhófà February 20-26 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Máa Fayọ̀ Ṣe Ohun Tágbára Ẹ Gbé Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà February 27–March 5 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣàṣeyọrí MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ Fi Ìlànà Bíbélì Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọn Lè Ṣàṣeyọrí TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ