-
Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Jẹ́ Aláyọ̀?—Apá KejìGbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
-
-
4. Máa fìfẹ́ bá àwọn ọmọ rẹ wí
Iṣẹ́ kékeré kọ́ ni láti tọ́ ọmọ. Báwo ni Bíbélì ṣe lè ran àwọn òbí lọ́wọ́? Ka Jémíìsì 1:19, 20, lẹ́yìn náà kó o dáhùn àwọn ìbéèrè yìí:
Báwo làwọn òbí ṣe lè fi hàn pé àwọn nífẹ̀ẹ́ àwọn ọmọ wọn tí wọ́n bá ń bá àwọn ọmọ wọn sọ̀rọ̀?
Kí nìdí tí kò fi yẹ kí òbí kan bá ọmọ rẹ̀ wí nígbà tínú ṣì ń bí òbí náà?a
-