ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 65
  • Ẹ Tẹ̀ Síwájú!

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ Tẹ̀ Síwájú!
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ Máa Tẹ̀ Síwájú!
    Kọrin sí Jèhófà
  • Ẹ Jẹ́ “Kí Ìmọ́lẹ̀ Yín Máa Tàn”
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Ẹ Jẹ́ “Kí Ìmọ́lẹ̀ Yín Máa Tàn” Kẹ́ Ẹ Lè Fògo fún Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • “Kí Ìmọ́lẹ̀ Yín Máa Tàn”
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2001
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 65

ORIN 65

Ẹ Tẹ̀ Síwájú!

Bíi Ti Orí Ìwé

(Hébérù 6:1)

  1. 1. Ẹ máa tẹ̀ síwájú, nínú òtítọ́.

    Ká tan ìmọ́lẹ̀ òótọ́ fún gbogbo aráyé.

    Jẹ́ kíṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ máa sunwọ̀n sí i;

    Kó o gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run.

    Gbogbo wa ló yẹ ká ṣiṣẹ́ yìí.

    Rántí pé Jésù náà ṣiṣẹ́ yìí.

    Máa bẹ Ọlọ́run pé kó dúró tì ọ́,

    Kó o lè jẹ́ olódodo.

  2. 2. Ẹ máa tẹ̀ síwájú, fìgboyà wàásù.

    Ká sọ ìròyìn ayọ̀ fún gbogbo aráyé.

    Ẹ jẹ́ ká máa wàásù látilé délé,

    Ká fi yin Jáà, Ọba wa.

    Báwọn ọ̀tá tiẹ̀ ń halẹ̀ mọ́ wa,

    Má bẹ̀rù, ṣáà máa fòótọ́ kọ́ni.

    Ká jẹ́ kí gbogbo èèyàn mọ̀ pé láìpẹ́,

    ’Jọba Ọlọ́run máa dé.

  3. 3. Ẹ máa tẹ̀ síwájú, ẹ má ṣe yẹsẹ̀.

    Ká sì máa sunwọ̀n sí i,

    Iṣẹ́ ṣì pọ̀ láti ṣe.

    Jẹ́ kí ẹ̀mí Ọlọ́run máa darí rẹ,

    Yóò sì máa fún ọ láyọ̀.

    Nífẹ̀ẹ́ àwọn tí ò ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́.

    Kọ́ wọn kí òótọ́ lè dọ́kàn wọn.

    Ràn wọ́n lọ́wọ́ kí wọ́n lè dàgbà dénú,

    Kí ‘mọ́lẹ̀ òótọ́ lè tàn.

(Tún wo Fílí. 1:27; 3:16; Héb. 10:39.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́