ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 122
  • Ẹ Fẹsẹ̀ Múlẹ̀ Ṣinṣin

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ Fẹsẹ̀ Múlẹ̀ Ṣinṣin
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ Fẹsẹ̀ Múlẹ̀ Ṣinṣin!
    Kọrin sí Jèhófà
  • “Ẹ Dúró Gbọn-in, Ẹ Má Yẹsẹ̀”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Yóò Sọ Ọ́ Di Alágbára
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Yóò Sọ Ọ́ Di Alágbára
    Kọrin sí Jèhófà
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 122

ORIN 122

Ẹ Fẹsẹ̀ Múlẹ̀ Ṣinṣin

Bíi Ti Orí Ìwé

(1 Kọ́ríńtì 15:58)

  1. 1. Hílàhílo ti dé bá aráyé;

    Wọn kò mọ ohun tá á ṣẹlẹ̀ lọ́la.

    Ó yẹ káwa fẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin,

    Ká fòótọ́ sin Ọlọ́run.

    (ÈGBÈ)

    Ó yẹ ká dúró ṣinṣin,

    Ká má ṣe báyé ṣọ̀rẹ́.

    Kí á jẹ́ olóòótọ́,

    Ká lè jogún ìyè.

  2. 2. Ìdẹwò pọ̀ gan-an nínú ayé yìí.

    Èrò tó tọ́ yóò mú ká borí wọn.

    Tá a bá kórìíra ohun tó burú,

    Yóò jẹ́ kẹ́sẹ̀ wa múlẹ̀.

    (ÈGBÈ)

    Ó yẹ ká dúró ṣinṣin,

    Ká má ṣe báyé ṣọ̀rẹ́.

    Kí á jẹ́ olóòótọ́,

    Ká lè jogún ìyè.

  3. 3. Ká jọ́sìn Ọlọ́run látọkàn wá;

    Ká sì tẹra mọ́ iṣẹ́ Olúwa.

    Ká wàásù Ìjọba náà fáráyé;

    Òpin ti fẹ́rẹ̀ẹ́ dé tán.

    (ÈGBÈ)

    Ó yẹ ká dúró ṣinṣin,

    Ká má ṣe báyé ṣọ̀rẹ́.

    Kí á jẹ́ olóòótọ́,

    Ká lè jogún ìyè.

(Tún wo Lúùkù 21:9; 1 Pét. 4:7.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́