ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sn orin 60
  • Yóò Sọ Ọ́ Di Alágbára

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Yóò Sọ Ọ́ Di Alágbára
  • Kọrin sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Yóò Sọ Ọ́ Di Alágbára
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Ó Yẹ Ká Ní Ìgbàgbọ́
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • À Ń Múra Láti Lọ Wàásù
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • À Ń Múra Láti Lọ Wàásù
    Kọrin sí Jèhófà—Àwọn Orin Tuntun
Àwọn Míì
Kọrin sí Jèhófà
sn orin 60

Orin 60

Yóò Sọ Ọ́ Di Alágbára

Bíi Ti Orí Ìwé

(1 Pétérù 5:10)

1. Ó nídìí tí Ọlọ́run

fi jẹ́ kóo róòótọ́,

Tó sì mú ọ wá sínú ìmọ́lẹ̀.

Ó ti rí ohun tó

wà ní ọkàn rẹ pé,

O ńwá òun, o sì ńfẹ́ ṣohun tó tọ́.

O wá jẹ́jẹ̀ẹ́ láti ṣe ìfẹ́ rẹ̀;

Títí láé ni yóò máa ràn ọ́ lọ́wọ́.

(ÈGBÈ)

Ẹ̀jẹ̀ Jésù ló fi rà ọ́,

tirẹ̀ lo sì jẹ́.

Yóò fẹsẹ̀ rẹ múlẹ̀,

yóò fún ọ lágbára.

Yóò ṣamọ̀nà rẹ, yóò pa

ọ́ mọ́ bó ti ńṣe bọ̀.

Yóò fẹsẹ̀ rẹ múlẹ̀,

yóò fún ọ lágbára.

2. Ọlọ́run jọ̀wọ́ Ọmọ rẹ̀ ọ̀wọ́n fún ọ;

Torí kí o bàa lè ṣe àṣeyè.

Bí kò sì ti fi Ọmọ rẹ̀ ọ̀wọ́n dù ọ́,

Má ṣe mikàn yóò fún ọ lágbára.

Kò ní gbàgbé iṣẹ́ òun ìfẹ́ rẹ;

Kò sì ní ṣàìtọ́jú ẹni tirẹ̀.

(ÈGBÈ)

Ẹ̀jẹ̀ Jésù ló fi rà ọ́,

tirẹ̀ lo sì jẹ́.

Yóò fẹsẹ̀ rẹ múlẹ̀,

yóò fún ọ lágbára.

Yóò ṣamọ̀nà rẹ, yóò pa

ọ́ mọ́ bó ti ńṣe bọ̀.

Yóò fẹsẹ̀ rẹ múlẹ̀,

yóò fún ọ lágbára.

(Tún wo Róòmù 8:32; 14:8, 9; Héb. 6:10; 1 Pét. 2:9.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́