ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 67
  • Wàásù Ọ̀rọ̀ Náà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wàásù Ọ̀rọ̀ Náà
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Wàásù Ọ̀rọ̀ Náà”
    Kọrin sí Jèhófà
  • À Ń Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • À Ń Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà
    Kọrin sí Jèhófà—Àwọn Orin Tuntun
  • Báwo La Ṣe Ń Wàásù Ìhìn Rere?
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 67

ORIN 67

Wàásù Ọ̀rọ̀ Náà

Bíi Ti Orí Ìwé

(2 Tímótì 4:2)

  1. 1. Jáà ti pàṣẹ fún wa lónìí,

    Ó sì yẹ ká ṣègbọràn sáṣẹ rẹ̀.

    Ká máa múra ọkàn wa sílẹ̀

    Láti sọ̀r’Ọlọ́run nígbàkigbà.

    (ÈGBÈ)

    Ṣáà máa wàásù

    Kí gbogbo èèyàn lè gbọ́.

    Máa wàásù;

    Òpin ayé ti dé tán.

    Máa wàásù;

    Kọ́ onírẹ̀lẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́.

    Máa wàásù

    Kárí ayé.

  2. 2. Àkókò ìṣòro yóò wà.

    Wọ́n lè ṣe inúnibíni sí wa.

    Bí wọn kò tiẹ̀ fẹ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ wa,

    Ẹ jẹ́ ká gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run wa.

    (ÈGBÈ)

    Ṣáà máa wàásù

    Kí gbogbo èèyàn lè gbọ́.

    Máa wàásù;

    Òpin ayé ti dé tán.

    Máa wàásù;

    Kọ́ onírẹ̀lẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́.

    Máa wàásù

    Kárí ayé.

  3. 3. Àkókò tó dẹrùn yóò wà,

    Táa máa ní àǹfààní láti kọ́ni.

    Ká wàásù kí wọ́n lè rígbàlà,

    Kórúkọ Jèhófà lè di mímọ́.

    (ÈGBÈ)

    Ṣáà máa wàásù

    Kí gbogbo èèyàn lè gbọ́.

    Máa wàásù;

    Òpin ayé ti dé tán.

    Máa wàásù;

    Kọ́ onírẹ̀lẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́.

    Máa wàásù

    Kárí ayé.

(Tún wo Mát. 10:7; 24:14; Ìṣe 10:42; 1 Pét. 3:15.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́