ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 132
  • A Ti Di Ọ̀kan Ṣoṣo

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • A Ti Di Ọ̀kan Ṣoṣo
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • A Ti Di Ọ̀kan Ṣoṣo
    Kọrin sí Jèhófà
  • Bá A Ṣe Lè Ṣe Ọ̀nà Wa Ní Rere
    Kọrin sí Jèhófà
  • Ìyanu Ni Ìwàláàyè Jẹ́
    Kọrin sí Jèhófà
  • Ìyanu Ni Ìwàláàyè Jẹ́
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 132

ORIN 132

A Ti Di Ọ̀kan Ṣoṣo

Bíi Ti Orí Ìwé

(Jẹ́nẹ́sísì 2:23, 24)

  1. 1. Èyí ni egungun tèmi.

    Jèhófà ló pèsè rẹ̀ fún mi.

    Mo ti wá ní ẹnì kejì;

    Èmi kò dá wà mọ́.

    A ti wá di ọ̀kan ṣoṣo;

    Kí Jáà bù kún àwa méjèèjì.

    A ti wá di ìdílé kan;

    A di tọkọtaya.

    A ó jọ máa sin Ọlọ́run pa pọ̀.

    A ó máa fara wé e,

    A ó fẹ́ra wa látọkàn.

    Bá a ṣe jẹ́jẹ̀ẹ́, bẹ́ẹ̀ ni kó rí.

    Kí ìtura, ayọ̀, wọlé wá.

    A ó máa fògo fún Jèhófà,

    A ó sì jọ bára wa kalẹ́.

(Tún wo Jẹ́n. 29:18; Oníw. 4:​9, 10; 1 Kọ́r. 13:8.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́