Bí Nǹkan Ṣe Rí Lára Ẹni, Ànímọ́ àti Ìwà
Tún wo Èso Ti Ẹ̀mí lábẹ́ Ìgbésí Ayé Kristẹni
Báwo Lèèyàn Ṣe Lè Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Gidi? Jí!, 7/2014
Ǹjẹ́—“Bẹ́ẹ̀ Ni” Rẹ Kì Í Di “Bẹ́ẹ̀ Kọ́”? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2014
Àwọn Ìwà Rere Tó Ń Mú Káyé Ẹni Dára Jí!, 1/2014
Báwo Ni Àwọ̀ Ṣe Ń Nípa Lórí Rẹ? Ilé Ìṣọ́, 10/1/2013
Àwọn Ànímọ́ Tá A Gbọ́dọ̀ Máa Lépa Ilé Ìṣọ́, 6/15/2008
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Ohun Tó Ń Ṣe Mí Mọ́ra? Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé, Apá Kejì, orí 26
Àánú àti Ìdáríjì
Ọ̀rọ̀ Ọgbọ́n Tó Wúlò Lóde Òní: Máa Dárí Jini Látọkànwá Ilé Ìṣọ́, 10/1/2015
Tẹ́ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: “Èmi Ha Wà ní Ipò Ọlọ́run Bí?” Ilé Ìṣọ́, 5/1/2015
Ẹ̀dùn Ọkàn—Bí Ẹnì Kan Bá Ṣẹ̀ Wá Pa Dà Sọ́dọ̀ Jèhófà, apá 3
Sún Mọ́ Ọlọ́run: “Jèhófà Dárí Jì Yín Fàlàlà” Ilé Ìṣọ́, 10/1/2013
Ó Kọ́ Ìdí Tó Fi Yẹ Kó Jẹ́ Aláàánú Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, orí 14
Ó Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Ìdáríjì Lọ́dọ̀ Ọ̀gá Rẹ̀ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, orí 23
Ẹ Máa Dárí Ji Ara Yín Fàlàlà Ilé Ìṣọ́, 11/15/2012
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: Ó Kọ́ Ìdáríjì Lọ́dọ̀ Ọ̀gá Rẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 4/1/2010
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: Ó Kọ́ Béèyàn Ṣe Lè Jẹ́ Aláàánú Ilé Ìṣọ́, 4/1/2009
Ẹ Máa Ṣe Rere (§ Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dárí Jini?) Ilé Ìṣọ́, 5/15/2008
Kọ́ Ọmọ Rẹ Láti Jẹ́ Ẹni Àlàáfíà (§ Kọ́ Ọmọ Rẹ Pé Ó Dára Láti Máa Dárí Jini) Ilé Ìṣọ́, 12/1/2007
Báwo La Ṣe Lè Máa Ṣàánú Ọmọnìkejì Wa? Ilé Ìṣọ́, 9/15/2007
“Jésù . . . Nífẹ̀ẹ́ Wọn Dé Òpin” (§ Bó Ṣe Máa Ń Wù Ú Láti Dárí Jini) “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” orí 16
Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dárí Jini Olùkọ́, orí 14
Ọlọ́run Tó “Ṣe Tán Láti Dárí Jini” Sún Mọ́ Jèhófà, orí 26
Àìní Iyì Lójú Ara-Ẹni àti Àìjámọ́ Nǹkan Kan
Bó O Ṣe Lè Máa Fi Ojú Tó Tọ́ Wo Nǹkan Ilé Ìṣọ́, 3/15/2014
Sún Mọ́ Ọlọ́run: Ǹjẹ́ Ọ̀rọ̀ Rẹ Jẹ Jèhófà Lógún Lóòótọ́? Ilé Ìṣọ́, 5/1/2013
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ló Dé Témi Ò Fi Mọ Nǹkan Kan Ṣe? Jí!, 7/2011
Sún Mọ́ Ọlọ́run: ‘Ó Tu Jèhófà Lójú’ Ilé Ìṣọ́, 1/1/2011
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Túbọ̀ Dá Ara Mi Lójú? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 12
Bí Mi Ò Bá Fẹ́ràn Bí Mo Ṣe Rí Ńkọ́? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 7
Jèhófà Ni “Olùsẹ̀san Fún Àwọn Tí Ń Fi Taratara Wá A” Ilé Ìṣọ́, 8/1/2005
Jèhófà Tóbi Ju Ọkàn-Àyà Wa Lọ Ilé Ìṣọ́, 5/1/2000
Àmúmọ́ra
Ojú Ìwòye Bíbélì: Àmúmọ́ra Jí!, 9/2015
Ṣé Lóòótọ́ Ni Ò Ń Rára Gba Nǹkan? Ilé Ìṣọ́, 7/15/2001
Àníyàn àti Ìbẹ̀rù
Ọ̀rọ̀ Ọgbọ́n Tó Wúlò Lóde Òní: Má Ṣe Máa Ṣàníyàn Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 1 2016
Ojú Ìwòye Bíbélì: Àníyàn Jí!, No. 2 2016
Ǹjẹ́ O Lè Pinnu Bí Ìgbésí Ayé Rẹ Ṣe Máa Rí?
Ohun tó jẹ́ ìṣòro: Ìṣòro Tó Kọjá Agbára Wa
Àníyàn Ìgbésí Ayé—“A Há Wa Gádígádí ní Gbogbo Ọ̀nà” Pa Dà Sọ́dọ̀ Jèhófà, apá 2
Ìbéèrè 16: Tí Àníyàn Bá Ń Dà Ọ́ Láàmù Báwo Lo Ṣe Lè Fara Dà Á? Ohun Tó Wà Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣé Ẹní Bá Ń Ṣàníyàn Ò Nígbàgbọ́ Ni? Jí!, 6/8/2004
“Ẹ Má Fòyà Tàbí Kí Ẹ Jáyà” Ilé Ìṣọ́, 6/1/2003
Ìrànlọ́wọ́ Láti Borí Ìbẹ̀rù Olùkọ́, orí 30
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dẹ́kun Dídààmú Kọjá Ààlà? Jí!, 10/8/2001
Àṣà Dáadáa àti Àṣà Burúkú
Fi Ohun Tó Dáa Kọ́ra Kó O Lè Rí Ìbùkún Rẹpẹtẹ Gbà Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 7/2006
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ǹjẹ́ Ó Ṣeé Ṣe Láti Jáwọ́ Nínú Àṣà Burúkú? Jí!, 4/8/2004
Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Ṣiṣẹ́ Olùkọ́, orí 42
Jẹ́ Kí Àwọn Àṣà Tó Ti Mọ́ Ọ Lára Ṣe Ọ́ Láǹfààní Ilé Ìṣọ́, 8/1/2001
Ayọ̀
Ẹ̀rín Músẹ́—Ẹ̀bùn Tó O Lè Fúnni Jí!, No. 1 2017
Ìbéèrè 15: Báwo lo ṣe lè rí ayọ̀? Ohun Tó Wà Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
Ṣé O Máa Ń Jẹ “Àsè Nígbà Gbogbo”? Jí!, 1/2014
Ṣé Wàá Fẹ́ Mọ Òtítọ́? (§ Báwo Ni Mo Ṣe Lè Jẹ́ Aláyọ̀?) Mọ Òtítọ́
Mọ̀ Dájú Pé O Lè Rí Ayọ̀ Ilé Ìṣọ́, 6/15/2006
Aláyọ̀ Ni Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 11/1/2004
Bí A Ṣe Lè Ní Ayọ̀ Olùkọ́, orí 17
Bí A Ṣe Lè Rí Ayọ̀ Tòótọ́ Ilé Ìṣọ́, 3/1/2001
Dídá Wà
Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Ohun Tó O Lè Ṣe Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bí I Pé O Kò Ní Ọ̀rẹ́ Jí!, 5/2015
Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Mi Ò Fi Ní Máa Dá Wà? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 9
Bíborí Ìṣòro Dídá Wà Jí!, 6/8/2004
O Lè Borí Ìnìkanwà Ilé Ìṣọ́, 3/15/2002
Dídé Lásìkò
Ojú Ìwòye Bíbélì: Dídé Lásìkò Jí!, No. 6 2016
Ẹ̀bi
Tún wo Àánú àti Ìdáríjì lábẹ́ Àwọn Ànímọ́ Jèhófà lábẹ́ Jèhófà Ọlọ́run
Ṣé Ò Ń Sá Di Jèhófà? Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 11/2017
Ẹ̀bi Ẹ̀ṣẹ̀—‘Wẹ̀ Mí Mọ́ Kúrò Nínú Ẹ̀ṣẹ̀ Mi’ Pa Dà Sọ́dọ̀ Jèhófà, apá 4
O Lè Sin Jèhófà Kó O Má Sì Kábàámọ̀ Ilé Ìṣọ́, 1/15/2013
Bó O Ṣe Lè Ní Ẹ̀rí Ọkàn Rere ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, orí 2
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣé Ohun Tó Burú Ni Kí Ẹ̀rí Ọkàn Máa Dá Èèyàn Lẹ́bi? Jí!, 3/8/2002
Ẹ̀mí Ìfọ̀rọ̀rora-Ẹni-Wò àti Ìyọ́nú
Máa Fàánú Hàn Bíi Ti Jèhófà Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 9/2017
Ẹ Fara Wé Ẹni Tó Ṣèlérí Ìyè Àìnípẹ̀kun Ilé Ìṣọ́, 5/15/2015
Ẹ Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ àti Oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ Bíi Ti Jésù Ilé Ìṣọ́, 2/15/2015
Bí A Ṣe Lè Tu Aláìsàn Tó Ń Retí Ikú Nínú Ilé Ìṣọ́, 5/1/2008
“Àánú Ṣe É” “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” orí 15
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣé Ọ̀dẹ̀ Lẹni Tó Bá Jẹ́ Èèyàn Pẹ̀lẹ́? Jí!, 1/8/2005
Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú Ilé Ìṣọ́, 5/1/2003
Ẹ̀mí Ìfọ̀rọ̀rora-Ẹni-Wò—Ń Jẹ́ Ká Ní Ojú Àánú àti Ìyọ́nú Ilé Ìṣọ́, 4/15/2002
Ìrànlọ́wọ́ Fáwọn Èèyàn Tí Wọ́n Dá Lóró Jí!, 1/8/2000
Ẹ̀tàn, Irọ́ Pípa àti Àgàbàgebè
Bí Àwọn Ìran Tí Sekaráyà Rí Ṣe Kàn Ẹ́ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 10/2017
Ṣé Ìwà Àgàbàgebè Lè Dópin? Ilé Ìṣọ́, 12/1/2015
Kọ́ Ọmọ Rẹ: Pétérù Parọ́, Ananíà Náà Parọ́—Ẹ̀kọ́ Wo Ni Èyí Kọ́ Wa? Ilé Ìṣọ́, 3/1/2013
Ìwà Ọ̀dàlẹ̀ Àmì Búburú Kan Tó Fi Hàn Pé À Ń Gbé Ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn! Ilé Ìṣọ́, 4/15/2012
Ṣọ́ra fún Ẹ̀tàn Ilé Ìṣọ́, 9/1/2010
Ṣé Ìwà Àìṣòótọ́ Ni? Ilé Ìṣọ́, 6/1/2010
Ta Ló Yẹ Kí N Sọ Fún Bí Mo Bá Ń Yọ́ Ìwà Tí Kò Tọ́ Hù? Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé, Apá Kejì, orí 16
Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Wọ́n Lù Ọ́ Ní Jìbìtì Jí!, 8/8/2004
Ṣọ́ra fún Ẹ̀tàn Ilé Ìṣọ́, 2/15/2004
Ìdí Tí Kò Fi Yẹ Ká Máa Purọ́ Olùkọ́, orí 22
Ojú Wo Lo Fi Ń Wo Ìwà Àgàbàgebè? Ilé Ìṣọ́, 11/15/2001
Wọ́n Lè Jí Ohun Ìdánimọ̀ Rẹ Lọ! Jí!, 4/8/2001
Ojú Ìwòye Bíbélì: Irọ́ Pípa—Ǹjẹ́ Àwíjàre Kankan Wà fún Un? Jí!, 2/8/2000
Gbẹ̀san
“Ẹ Jẹ́ Ẹlẹ́mìí Àlàáfíà Pẹ̀lú Gbogbo Ènìyàn” (§ Ti Jèhófà Ni Ẹ̀san) Ilé Ìṣọ́, 10/15/2009
Táwọn Èèyàn Bá Ṣe Ohun Tó Dùn Ẹ́ Ilé Ìṣọ́, 9/1/2009
“Ẹ Má Ṣe Fi Ibi San Ibi Fún Ẹnì Kankan” Ilé Ìṣọ́, 7/1/2007
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Gbẹ̀san? Jí!, 11/8/2001
Ìbínú àti Ìkórìíra
Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí O Ṣe Lè Ṣàkóso Ìbínú Rẹ Jí!, 3/2015
“Ìjìnlẹ̀ Òye Tí Ènìyàn Ní Máa Ń Dẹwọ́ Ìbínú Rẹ̀” Ilé Ìṣọ́, 12/1/2014
Báwo La Ṣe Lè Yanjú Aáwọ̀? Jí!, 9/2014
Máa Ṣàkóso Ìbínú Rẹ Kó O Lè “Máa Fi Ire Ṣẹ́gun Ibi” Ilé Ìṣọ́, 6/15/2010
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Máa Bínú Sódì? Jí!, 10/2009
Ẹ Má Ṣe Fàyè Sílẹ̀ fún Èṣù Ilé Ìṣọ́, 1/15/2006
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Jà? Olùkọ́, orí 19
Kí Ló Ń Mú Kí Ìbínú Máa Ru Bo Àwọn Èèyàn Lójú Tó Bẹ́ẹ̀? Jí!, 2/8/2002
Bí A Ṣe Lè Fòpin sí Ìwà Ìkórìíra Jí!, 8/8/2001
Ọ̀nà Kan Ṣoṣo Tí A Lè Gbà Mú Ìkórìíra Kúrò Pátápátá Ilé Ìṣọ́, 8/15/2000
Ìdúpẹ́
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ẹ̀mí Ìmoore Jí!, No. 5 2016
Fi Ọpẹ́ Fún Jèhófà Kí O sì Gba Ìbùkún Ilé Ìṣọ́, 1/15/2015
Ṣé O Mọyì Àwọn Ìbùkún Tó O Ní Lóòótọ́? Ilé Ìṣọ́, 2/15/2011
‘Ẹ Máa Kún fún Ọpẹ́’ Ilé Ìṣọ́, 12/1/2003
Ǹjẹ́ O Máa Ń Rántí Láti Dúpẹ́? Olùkọ́, orí 18
Ìdúróṣinṣin àti Ẹni Tó Ṣeé Fọkàn Tán
‘Orúkọ Rere Dára Ju Ọ̀pọ̀ Yanturu Ọrọ̀ Lọ’ Jí!, No. 4 2017
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìdúróṣinṣin Ítítáì Ilé Ìṣọ́, 5/15/2009
Ìwọ Kò Gbọ́dọ̀ Gbàgbé Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 3/15/2009
Máa Bá A Nìṣó Láti Jẹ́ Adúróṣinṣin Pẹ̀lú Ọkàn Tó Ṣọ̀kan Ilé Ìṣọ́, 8/15/2008
Àwọn Tó Dúró Ṣinṣin Tí Wọn Ò Bọ́hùn Láyé Àtijọ́ àti Lóde Òní Ilé Ìṣọ́, 10/15/2004
Ẹ Fi Ìdúróṣinṣin Tẹrí Ba fún Ọlá Àṣẹ Ọlọ́run Ilé Ìṣọ́, 8/1/2002
Kí Ni Jíjẹ́ Adúróṣinṣin Túmọ̀ Sí? Ilé Ìṣọ́, 10/1/2001
Ìfẹ́ni
Ìdí Tó Fi Ṣe Pàtàkì Pé Ká Máa Fìfẹ́ Hàn Jí!, 1/2010
Ìfòyemọ̀
Ẹ Jẹ́ Onígboyà Kẹ́ Ẹ sì Máa Lo Ìfòyemọ̀ Bíi Ti Jésù Ilé Ìṣọ́, 2/15/2015
Ìfọkàntánni
Fífọkàntánni Ló Ń Mú Kí Ìgbésí Ayé Èèyàn Láyọ̀ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2003
Ìgbéraga àti Ìkùgbù
Ìṣọ̀kan La Fi Ń Dá Ìsìn Tòótọ́ Mọ̀ (§ Bá A Ṣe Lè Borí Ìgbéraga àti Owú) Ilé Ìṣọ́, 9/15/2010
Ẹ̀kọ́ Nípa Ẹ̀mí Ìgbéraga àti Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 6/15/2006
Má Ṣe Ní Ẹ̀mí Ìgbéraga Ilé Ìṣọ́, 10/15/2005
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣó Burú Kéèyàn Máa Wá Ipò Ọlá Ni? Jí!, 6/8/2005
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Fọ́nnu? Olùkọ́, orí 21
Ìkùgbù Máa Ń Fa Àbùkù Ilé Ìṣọ́, 8/1/2000
Ojú Wo Lo Fi Ń Wo Ara Rẹ? Ilé Ìṣọ́, 1/15/2000
Àwọn Ọmọ Ẹ̀yìn Ń Jiyàn Bí Ikú Jésù Ti Ń Sún Mọ́lé Ọkùnrin Títóbilọ́lá Jù Lọ, orí 98
Ìgboyà
“Jẹ́ Onígboyà . . . Kí O sì Gbé Ìgbésẹ̀” Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 9/2017
Àwọn Ànímọ́ Kristẹni Tó Yẹ Kó O Ní—Ìgboyà Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 8/2017
Ẹ Jẹ́ Onígboyà Kẹ́ Ẹ sì Máa Lo Ìfòyemọ̀ Bíi Ti Jésù Ilé Ìṣọ́, 2/15/2015
Onígboyà Ni Mọ̀lẹ́bí Pọ́ọ̀lù Kọ́ Ọmọ Rẹ, ẹ̀kọ́ 12
“Jẹ́ Onígboyà àti Alágbára Gidigidi” Ilé Ìṣọ́, 2/15/2012
Ìgbàgbọ́ àti Ìbẹ̀rù Ọlọ́run Fún Wọn Ní Ìgboyà Ilé Ìṣọ́, 10/1/2006
Ìlara àti Owú
Ìlara Lè Mú Kéèyàn Ní Èròkerò Ilé Ìṣọ́, 2/15/2012
Àárín Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Lo Ti Lè Rí Ààbò (§ “Ẹsẹ̀ Mi Fẹ́rẹ̀ẹ́ Yà Kúrò Lọ́nà”) Ilé Ìṣọ́, 6/15/2010
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kó O Máa Fi Ara Ẹ Wé Àwọn Ẹlòmíì? (§ Bá A Ṣe Lè Gbógun Ti Ìlara) Ilé Ìṣọ́, 2/15/2005
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kí Kristẹni Máa Jowú? Ilé Ìṣọ́, 10/15/2002
Ìkùgbù Máa Ń Fa Àbùkù (§ Dènà “Ìtẹ̀sí Láti Ṣe Ìlara”) Ilé Ìṣọ́, 8/1/2000
Ìmẹ̀tọ́mọ̀wà
Básíláì Ọkùnrin Tó Mọ̀wọ̀n Ara Ẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 7/15/2007
“Ọgbọ́n Wà Pẹ̀lú Àwọn Amẹ̀tọ́mọ̀wà” Ilé Ìṣọ́, 8/1/2000
Ìmẹ̀tọ́mọ̀wà—Ànímọ́ Tó Ń Gbé Àlàáfíà Lárugẹ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2000
Ìmọtara-Ẹni-Nìkan
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kó O Máa Rin Kinkin Mọ́ Ohun Tó Bá Ṣáà Ti Wù Ọ́? Ilé Ìṣọ́, 2/15/2009
Jèhófà Ń dáàbò Bo Àwọn Tó Ní Ìrètí Nínú Rẹ̀ (§ Dídi Onímọtara-Ẹni-Nìkan Léwu) Ilé Ìṣọ́, 6/1/2005
Ǹjẹ́ O Máa Ń Fẹ́ Jẹ́ Ẹni Àkọ́kọ́ Nígbà Gbogbo? Olùkọ́, orí 20
Bó O Ṣe Lè Kẹ́sẹ Járí Nínú Ayé Alálòsọnù Jí!, 9/8/2002
Ìrẹ̀lẹ̀
Àwọn Ànímọ́ Kristẹni Tó Yẹ Kó O Ní—Ìrẹ̀lẹ̀ Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 8/2017
Ẹ Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ àti Oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ Bíi Ti Jésù Ilé Ìṣọ́, 2/15/2015
Máa Hùwà Bí Ẹni Tó Kéré Jù Ilé Ìṣọ́, 11/15/2012
“Ẹ Ṣọ́ra fún Ìwúkàrà Àwọn Farisí” Ilé Ìṣọ́, 5/15/2012
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣé Ọ̀dẹ̀ Lẹní Bá Níwà Ìrẹ̀lẹ̀ àbí Ọlọgbọ́n? Jí!, 4/2007
Ẹ̀kọ́ Wo Lo Lè Rí Kọ́ Lára Àwọn Ọmọdé? Ilé Ìṣọ́, 2/1/2007
“Ẹni Rírẹlẹ̀ ní Ọkàn-Àyà Ni Èmi” “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” orí 3
Ní Ojúlówó Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ (§ Ẹni Tí Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ Rẹ̀ Ga Jù Lọ) Ilé Ìṣọ́, 10/15/2005
Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí La Fi Gbà Wọ́n Là, Kì í Ṣe Iṣẹ́ Nìkan Ilé Ìṣọ́, 6/1/2005
Olùkọ́ Ńlá Náà Sin Àwọn Ẹlòmíràn Olùkọ́, orí 6
Ìrẹ̀wẹ̀sì, Àìláyọ̀ àti Ìsoríkọ́
Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ní Ìdààmú Ọkàn Jí!, No. 1 2017
Máa Fayọ̀ Sin Jèhófà Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 2/2016
Ó Lo Ìfaradà Bó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Wọ́n Já A Kulẹ̀ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, orí 8
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: Ó Fara Da Ìjákulẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 1/1/2011
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Ìbànújẹ́ Kúrò Lọ́kàn Mi? Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé, Apá Kìíní, orí 13
Báwo Lo Ṣe Lè Borí Èrò Òdì? Ilé Ìṣọ́, 10/1/2010
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Ìbànújẹ́ Kúrò Lọ́kàn Mi? Jí!, 10/2010
Bí A Ṣe Lè Borí Èrò Òdì Ilé Ìṣọ́, 4/15/2001
O Mà Lè Borí Ìrẹ̀wẹ̀sì! Ilé Ìṣọ́, 2/1/2001
Kí Ló Ń Mú Ọ Sin Ọlọ́run? Ilé Ìṣọ́, 12/15/2000
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Ṣé Kí N Sọ Fún Ẹnì Kan Pé Mo Níṣòro Ìsoríkọ́? Jí!, 11/8/2000
Láìpẹ́ Ayé Téèyàn Ò Ti Ní Bọ́hùn Mọ́ Yóò Dé Ilé Ìṣọ́, 9/15/2000
Ojú Ìwòye Bíbélì: Bí A Ṣe Lè Kápá Àìnírètí Jí!, 5/8/2000
Ìwà Funfun
Ìwà Ọ̀làwọ́
❐ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 6 2017
“Ẹ̀bùn Tó Dáa Jù Tí Mo Rí Gbà Nìyí”
Èrè Tó Wà Nínú Fífúnni Ní Nǹkan Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 2 2017
Sún Mọ́ Ọlọ́run: “Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Olùfúnni Ọlọ́yàyà” Ilé Ìṣọ́, 9/1/2013
Ìwọra
Ojú Ìwòye Bíbélì: Tẹ́tẹ́ Títa Jí!, 5/2015
‘Ṣọ́ra fún Onírúurú Ojúkòkòrò’ Ilé Ìṣọ́, 8/1/2007
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ojú wo ni ìjọ Kristẹni fi ń wo jíjẹ àjẹkì? Ilé Ìṣọ́, 11/1/2004
Jíjẹ́ Olóòótọ́
Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe tí Mo Bá Ṣàṣìṣe? Ìbéèrè 10, ìbéèrè 4
Ìwà Rere Tó Ṣeyebíye Ju Dáyámọ́ǹdì Lọ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 6/2016
Bá A Ṣe Lè Jẹ́ Olóòótọ́ Nínú Ayé Aláìṣòótọ́ Yìí Ilé Ìṣọ́, 4/15/2011
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kó O Jẹ́ Olóòótọ́ Ní Gbogbo Ìgbà? Ilé Ìṣọ́, 3/1/2010
Máa Bá Aládùúgbò Rẹ Sọ Òtítọ́ Ilé Ìṣọ́, 6/15/2009
Jẹ́ Olóòótọ́ Nínú Ohun Gbogbo ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 14
Ìṣòtítọ́ Lérè Ilé Ìṣọ́, 12/1/2006
Jíjíwèé Wò
Ṣé Ó Dáa Kéèyàn Jí Ìwé Wò Kó Lè Gba Máàkì Tó Pọ̀? Jí!, 10/2012
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ló Burú Nínú Jíjíwèé Wò? Jí!, 2/8/2003
Ọgbọ́n
Ǹjẹ́ Ò Ń “Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Ọgbọ́n Tí Ó Gbéṣẹ́”? Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 10/2016
Ọgbọ́n Inú
Kíkọ́ Bá A Ṣe Lè Máa Fọgbọ́n Bá Àwọn Èèyàn Lò Ilé Ìṣọ́, 8/1/2003
Ọ̀rọ̀ Tó Dáa
Máa Fi Ahọ́n Rẹ Sọ̀rọ̀ Tó Ń Gbéni Ró Ilé Ìṣọ́, 12/15/2015
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ìdí Tó Fi Yẹ Kó O Máa Ṣọ́ Ẹnu Rẹ Jí!, 7/2011
Jẹ́ Kí “Òfin Inú-rere-onífẹ̀ẹ́” Máa Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Ahọ́n Rẹ Ilé Ìṣọ́, 8/15/2010
“Ìgbà Dídákẹ́” Ilé Ìṣọ́, 5/15/2009
Ẹ Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Ẹnu Yín “Dára fún Gbígbéniró” ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 12
“Ìgbà Dídákẹ́” Ilé Ìṣọ́, 5/15/2009
Ǹjẹ́ Àwọn Èèyàn Ń Rí Ìtura Lọ́dọ̀ Rẹ? Ilé Ìṣọ́, 11/15/2007
Jíjíròrò Ohun Tẹ̀mí Ń Gbéni Ró Ilé Ìṣọ́, 9/15/2003
Ọ̀wọ̀
Ẹ Máa Bọlá fún Àwọn Tí Ọlá Tọ́ Sí Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 3/2017
Irú Ẹ̀mí Wo Lò Ń Fi Hàn? Ilé Ìṣọ́, 10/15/2012
Ṣé O Ń Mú Ipò Iwájú Nínú Bíbu Ọlá Fáwọn Èèyàn? Ilé Ìṣọ́, 10/15/2008
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Bọ̀wọ̀ Fáwọn Aláṣẹ? ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 4
Sísọ̀rọ̀ Tí Kò Dáa Lẹ́nu
Má Ṣe “Kún Fún Ìhónú Sí Jèhófà” Ilé Ìṣọ́, 8/15/2013
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Tí Mo Fi Sọ Irú Ọ̀rọ̀ Yìí? Jí!, 4/2012
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Máa Ṣépè? Jí!, 4/2008
Ẹ Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Ẹnu Yín “Dára fún Gbígbéniró” (§ Ọ̀rọ̀ Tí Kò Buyì Kúnni) ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 12
Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Máa Sọ̀rọ̀ Ẹlòmí ì Lẹ́yìn? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 12
Ẹ Má Ṣe Fàyè Sílẹ̀ fún Èṣù (§ Má Ṣe Fìwà Jọ Olórí Afọ̀rọ̀-Èké-Banijẹ́ Náà) Ilé Ìṣọ́, 1/15/2006
Ojú Ìwòye Bíbélì: Yẹra fún Sísọ Ọ̀rọ̀ Tó Máa Ń Dunni Jí!, 6/8/2003
Ṣé Àwọn Alárìíwísí Ò Tíì Kó Èèràn Ràn ọ́? Ilé Ìṣọ́, 7/15/2000
Sùúrù
Ẹ Máa Mú Sùúrù Bíi Ti Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 2/1/2006
Irú Ẹ̀mí Ìdúródeni Wo Lo Ní? Ilé Ìṣọ́, 10/1/2004
Ǹjẹ́ O Ní “Ẹ̀mí Ìdúródeni”? Ilé Ìṣọ́, 7/15/2003
Ẹ Fi Ẹ̀mí Ìdúródeni Hàn! Ilé Ìṣọ́, 9/1/2000