Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa? Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa? Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí ORÍ Kí Ni Ọlọ́run Ní Lọ́kàn fún Wa? ORÍ KÌÍNÍ Ta Ni Ọlọ́run? ORÍ KEJÌ Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Bíbélì Ti Wá ORÍ KẸTA Kí Ni Ọlọ́run Ní Lọ́kàn fún Aráyé? ORÍ KẸRIN Ta Ni Jésù Kristi? ORÍ KARÙN-ÚN Ìràpadà Ni Ẹ̀bùn Tó Dáa Jù Lọ Tí Ọlọ́run Fún Wa ORÍ KẸFÀ Ibo Là Ń Lọ Tá A Bá Kú? ORÍ KEJE Àjíǹde Máa Wà! ORÍ KẸJỌ Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? ORÍ KẸSÀN-ÁN Ṣé Òpin Ayé Ti Sún Mọ́lé? ORÍ KẸWÀÁ Ohun Tó Jẹ́ Òótọ́ Nípa Àwọn Áńgẹ́lì ORÍ KỌKÀNLÁ Kí Nìdí Tí Ìyà Fi Pọ̀ Láyé? ORÍ KEJÌLÁ Kí Lo Lè Ṣe Láti Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run? ORÍ KẸTÀLÁ Bọ̀wọ̀ fún Ẹ̀mí ORÍ KẸRÌNLÁ Ìdílé Rẹ Lè Láyọ̀ ORÍ KẸẸ̀Ẹ́DÓGÚN Ọ̀nà Tó Tọ́ Láti Jọ́sìn Ọlọ́run ORÍ KẸRÌNDÍNLÓGÚN Pinnu Láti Jọ́sìn Ọlọ́run ORÍ KẸTÀDÍNLÓGÚN Àǹfààní Pàtàkì Ni Àdúrà Jẹ́ ORÍ KEJÌDÍNLÓGÚN Ṣé Ó Yẹ Kí N Ya Ìgbésí Ayé Mi Sí Mímọ́ fún Ọlọ́run, Kí N sì Ṣe Ìrìbọmi? ORÍ KỌKÀNDÍNLÓGÚN Dúró Sọ́dọ̀ Jèhófà ÀLÀYÉ ÌPARÍ ÌWÉ Àlàyé Ìparí Ìwé