Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?
Ibi Tí A Ti Mú Àwọn Àwòrán:
◼ Ojú ìwé 25: Fọ́tò WHO tí Edouard Boubat yà
◼ Ojú ìwé 96 àti 97: Bọ́ǹbù tó bú gbàù: Látinú fọ́tò USAF; ọmọdé: Fọ́tò WHO tí W. Cutting yà
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
A Tẹ̀ Ẹ́ ní September 2019
Yoruba (bhs-YR)
© 2019
Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania