SEKARÁYÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Jèhófà ní kí wọ́n pa dà sọ́dọ̀ òun (1-6)
Ìran 1: Àwọn tó ń gun ẹṣin láàárín àwọn igi mátílì (7-17)
Ìran 2: Ìwo mẹ́rin àti oníṣẹ́ ọnà mẹ́rin (18-21)
2
3
4
5
6
7
8
9
10
Jèhófà ni kí ẹ bẹ̀ pé kó rọ̀jò, kì í ṣe àwọn ọlọ́run èké (1, 2)
Jèhófà mú kí àwọn èèyàn rẹ̀ wà níṣọ̀kan (3-12)
11
12
13
14