ÌṢE ÀWỌN ÀPỌ́SÍTÉLÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ó kọ̀wé sí Tìófílọ́sì (1-5)
Iṣẹ́ ìwàásù máa dé gbogbo ìkángun ayé (6-8)
Jésù gòkè lọ sọ́run (9-11)
Àwọn ọmọ ẹ̀yìn kóra jọ ní ìṣọ̀kan (12-14)
Wọ́n yan Màtáyásì rọ́pò Júdásì (15-26)
2
Ẹ̀mí mímọ́ tú jáde ní Pẹ́ńtíkọ́sì (1-13)
Ọ̀rọ̀ Pétérù (14-36)
Ọ̀pọ̀ èèyàn gba ọ̀rọ̀ tí Pétérù sọ (37-41)
Ìbákẹ́gbẹ́ Kristẹni (42-47)
3
4
Wọ́n mú Pétérù àti Jòhánù (1-4)
Ìgbẹ́jọ́ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (5-22)
Àdúrà ìgboyà (23-31)
Àwọn ọmọ ẹ̀yìn jọ pín ohun tí wọ́n ní (32-37)
5
Ananáyà àti Sàfírà (1-11)
Àwọn àpọ́sítélì ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì (12-16)
Wọ́n fi wọ́n sẹ́wọ̀n, wọ́n sì dá wọn sílẹ̀ (17-21a)
Wọ́n tún mú wọn wá síwájú Sàhẹ́ndìrìn (21b-32)
Ìmọ̀ràn Gàmálíẹ́lì (33-40)
Wọ́n ń wàásù láti ilé dé ilé (41, 42)
6
7
8
Sọ́ọ̀lù ṣe inúnibíni (1-3)
Ìwàásù Fílípì sèso rere ní Samáríà (4-13)
Wọ́n rán Pétérù àti Jòhánù lọ sí Samáríà (14-17)
Símónì fẹ́ ra ẹ̀mí mímọ́ (18-25)
Ìwẹ̀fà ará Etiópíà (26-40)
9
Sọ́ọ̀lù wà ní ọ̀nà Damásíkù (1-9)
Olúwa rán Ananáyà pé kó lọ ran Sọ́ọ̀lù lọ́wọ́ (10-19a)
Sọ́ọ̀lù wàásù nípa Jésù ní Damásíkù (19b-25)
Sọ́ọ̀lù wá sí Jerúsálẹ́mù (26-31)
Pétérù wo Énéà sàn (32-35)
Dọ́káàsì tó jẹ́ ọ̀làwọ́ jíǹde (36-43)
10
Ìran tí Kọ̀nílíù rí (1-8)
Pétérù rí àwọn ẹranko tí a ti sọ di mímọ́ nínú ìran (9-16)
Pétérù wá sílé Kọ̀nílíù (17-33)
Pétérù kéde ìhìn rere fún àwọn Kèfèrí (34-43)
Àwọn Kèfèrí gba ẹ̀mí mímọ́, wọ́n sì ṣèrìbọmi (44-48)
11
Pétérù ròyìn fún àwọn àpọ́sítélì (1-18)
Bánábà àti Sọ́ọ̀lù wà ní Áńtíókù ti Síríà (19-26)
Ágábù sọ tẹ́lẹ̀ pé ìyàn máa mú (27-30)
12
Wọ́n pa Jémíìsì; wọ́n fi Pétérù sẹ́wọ̀n (1-5)
Ọlọ́run dá Pétérù sílẹ̀ lọ́nà ìyanu (6-19)
Áńgẹ́lì kọ lu Hẹ́rọ́dù (20-25)
13
Wọ́n rán Bánábà àti Sọ́ọ̀lù láti lọ ṣe míṣọ́nnárì (1-3)
Iṣẹ́ ìwàásù ní Sápírọ́sì (4-12)
Ọ̀rọ̀ tí Pọ́ọ̀lù sọ ní Áńtíókù ti Písídíà (13-41)
Àsọtẹ́lẹ̀ tó fún wọn láṣẹ láti yíjú sí àwọn orílẹ̀-èdè (42-52)
14
Ní Íkóníónì, àwọn ọmọ ẹ̀yìn ń pọ̀ sí i, inúnibíni sì ń ṣẹlẹ̀ (1-7)
Ní Lísírà, wọ́n rò pé ọlọ́run ni wọ́n (8-18)
Wọ́n sọ Pọ́ọ̀lù lókùúta, àmọ́ kò kú (19, 20)
Wọ́n ń fún àwọn ìjọ lókun (21-23)
Wọ́n pa dà sí Áńtíókù ti Síríà (24-28)
15
Awuyewuye ní Áńtíókù lórí ọ̀rọ̀ ìdádọ̀dọ́ (1, 2)
Wọ́n gbé ọ̀rọ̀ náà lọ sí Jerúsálẹ́mù (3-5)
Àwọn alàgbà àti àwọn àpọ́sítélì ṣèpàdé (6-21)
Lẹ́tà látọ̀dọ̀ ìgbìmọ̀ olùdarí (22-29)
Lẹ́tà náà gbé àwọn ìjọ ró (30-35)
Pọ́ọ̀lù àti Bánábà lọ ní ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ (36-41)
16
Pọ́ọ̀lù mú Tímótì (1-5)
Ìran ọkùnrin ará Makedóníà (6-10)
Lìdíà di onígbàgbọ́ ní ìlú Fílípì (11-15)
Wọ́n ju Pọ́ọ̀lù àti Sílà sẹ́wọ̀n (16-24)
Ẹni tó ń ṣọ́ àwọn ẹlẹ́wọ̀n àti agbo ilé rẹ̀ ṣèrìbọmi (25-34)
Pọ́ọ̀lù ní kí àwọn aláṣẹ wá tọrọ àforíjì (35-40)
17
Pọ́ọ̀lù àti Sílà ní Tẹsalóníkà (1-9)
Pọ́ọ̀lù àti Sílà ní Bèróà (10-15)
Pọ́ọ̀lù ní Áténì (16-22a)
Ọ̀rọ̀ Pọ́ọ̀lù ní Áréópágù (22b-34)
18
Iṣẹ́ ìwàásù Pọ́ọ̀lù ní Kọ́ríńtì (1-17)
Ó pa dà sí Áńtíókù ti Síríà (18-22)
Pọ́ọ̀lù lọ sí Gálátíà àti Fíríjíà (23)
Àpólò tó jẹ́ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ rí ìrànlọ́wọ́ gbà (24-28)
19
Pọ́ọ̀lù ní Éfésù; àwọn kan tún batisí ṣe (1-7)
Àwọn ohun tí Pọ́ọ̀lù ṣe láti kọ́ni (8-10)
Ó ń ṣàṣeyọrí láìka àwọn tó ní ẹ̀mí èṣù sí (11-20)
Éfésù dà rú (21-41)
20
Pọ́ọ̀lù ní Makedóníà àti ilẹ̀ Gíríìsì (1-6)
Yútíkọ́sì jíǹde ní Tíróásì (7-12)
Láti Tíróásì sí Mílétù (13-16)
Pọ́ọ̀lù bá àwọn alàgbà Éfésù ṣèpàdé (17-38)
21
Lójú ọ̀nà Jerúsálẹ́mù (1-14)
Wọ́n dé Jerúsálẹ́mù (15-19)
Pọ́ọ̀lù tẹ̀ lé ìmọ̀ràn àwọn alàgbà (20-26)
Inú tẹ́ńpìlì dà rú; wọ́n mú Pọ́ọ̀lù (27-36)
Wọ́n gba Pọ́ọ̀lù láyè kó bá ọ̀pọ̀ èèyàn sọ̀rọ̀ (37-40)
22
23
Pọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (1-10)
Olúwa fún Pọ́ọ̀lù lókun (11)
Wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Pọ́ọ̀lù (12-22)
Wọ́n gbé Pọ́ọ̀lù lọ sí Kesaríà (23-35)
24
Wọ́n fẹ̀sùn kan Pọ́ọ̀lù (1-9)
Pọ́ọ̀lù gbèjà ara rẹ̀ níwájú Fẹ́líìsì (10-21)
Wọ́n dá ẹjọ́ Pọ́ọ̀lù dúró fún ọdún méjì (22-27)
25
Pọ́ọ̀lù jẹ́jọ́ níwájú Fẹ́sítọ́ọ̀sì (1-12)
Fẹ́sítọ́ọ̀sì fọ̀rọ̀ lọ Ọba Ágírípà (13-22)
Pọ́ọ̀lù dúró níwájú Ágírípà (23-27)
26
Pọ́ọ̀lù gbèjà ara rẹ̀ níwájú Ágírípà (1-11)
Pọ́ọ̀lù ṣàlàyé bó ṣe yí pa dà (12-23)
Èsì Fẹ́sítọ́ọ̀sì àti ti Ágírípà (24-32)
27
28
Wọ́n gúnlẹ̀ sí Málítà (1-6)
Bàbá Púbílọ́sì rí ìwòsàn (7-10)
Wọ́n forí lé Róòmù (11-16)
Pọ́ọ̀lù bá àwọn Júù sọ̀rọ̀ ní Róòmù (17-29)
Pọ́ọ̀lù fi ìgboyà wàásù fún ọdún méjì (30, 31)