2 KỌ́RÍŃTÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
2
Ó ń wu Pọ́ọ̀lù láti mú kí wọ́n láyọ̀ (1-4)
Ẹlẹ́ṣẹ̀ tí wọ́n dárí jì, tí wọ́n sì gbà pa dà (5-11)
Pọ́ọ̀lù lọ sí Tíróásì àti Makedóníà (12, 13)
Iṣẹ́ òjíṣẹ́ jẹ́ ìjáde àwọn tó ń yọ ayọ̀ ìṣẹ́gun (14-17)
3
4
5
6
Kí a má ṣi inú rere Ọlọ́run lò (1, 2)
Bí iṣẹ́ òjíṣẹ́ Pọ́ọ̀lù ṣe rí (3-13)
Ẹ má fi àìdọ́gba so pọ̀ (14-18)
7
Ká wẹ ara wa mọ́ kúrò nínú ẹ̀gbin (1)
Inú Pọ́ọ̀lù dùn sí àwọn ará Kọ́ríńtì (2-4)
Títù mú ìròyìn rere wá (5-7)
Ìbànújẹ́ ní ọ̀nà Ọlọ́run àti ìrònúpìwàdà (8-16)
8
9
10
11
12
Àwọn ìran tí Pọ́ọ̀lù rí (1-7a)
‘Ẹ̀gún nínú ara’ Pọ́ọ̀lù (7b-10)
Àwọn àpọ́sítélì adára-má-kù-síbìkan ò sàn jù ú lọ (11-13)
Bí ọ̀rọ̀ àwọn ará Kọ́ríńtì ṣe jẹ Pọ́ọ̀lù lógún (14-21)
13