Ṣé Inú Rẹ Á Dùn Láti Rí Ìtùnú Gbà?
Gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ní ojú ìwé 12, ọ̀pọ̀ èèyàn ló ti rí ìtùnú gbà nígbà tí wọ́n gbọ́ ohun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ọ̀ràn pàtàkì kan, bí irú àwọn tó wà nínú àwọn ìtẹ̀jáde olójú ìwé 32 yìí. O lè béèrè fún ẹ̀dà kan nípa kíkàn sí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ládùúgbò rẹ. Bó o bá fẹ́ kí ẹnì kan wá ọ wá, jọ̀wọ́ kọ̀wé sínú fọ́ọ̀mù tó wà nísàlẹ̀ yìí, kí o sì fi ránṣẹ́ sí àdírẹ́sì tá a kọ síbẹ̀ tàbí sí àdírẹ́sì tó yẹ lára èyí tí a tò sí ojú ìwé 5 nínú ìwé ìròyìn yìí.
□ Ẹ jọ̀wọ́, ẹ kàn sí mi nípa ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì inú ilé lọ́fẹ̀ẹ́.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 32]
Fọ́tò AP/Gulnara Samoilova