ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g19 No. 3 ojú ìwé 14-15
  • Ìwé Tó Dáa Jù Lọ Láyé

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìwé Tó Dáa Jù Lọ Láyé
  • Jí!—2019
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ÌTUMỌ̀ BÍBÉLÌ ÀTI IYE TÓ TI DỌ́WỌ́ ÀWỌN ÈÈYÀN
  • MỌ PÚPỌ̀ SÍ I
  • ÀWỌN BÍBÉLÌ TÍ ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ TI TẸ̀ JÁDE
  • BÍBÉLÌ ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN
  • Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ọ̀kẹ́ Àìmọye Èèyàn Mọyì Rẹ̀ Kárí Ayé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2001
  • Jèhófà Máa Ń Bá Àwa Èèyàn Sọ̀rọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2015
  • Ìṣẹ̀lẹ̀ Mánigbàgbé Fáwọn Tó Fẹ́ràn Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
  • Bí Bíbélì Ṣe Tẹ̀ Wá Lọ́wọ́
    Jí!—2007
Àwọn Míì
Jí!—2019
g19 No. 3 ojú ìwé 14-15
Obìnrin kan ń ka Bíbélì

Ìwé Tó Dáa Jù Lọ Láyé

Bíbélì ni ìwé tí wọ́n túmọ̀ sí èdè tó pọ̀ jù láyé yìí, òun sì ni ìwé tí wọ́n pín kiri jù lọ. Torí náà, ọgbọ́n inú rẹ̀ ti dé ibi gbogbo láyé, ó sì ti ran ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́wọ́ kárí ayé. Kò sí ìwé míì tó tíì ṣe irú ẹ̀ láyé yìí. Àwọn ìsọfúnni díẹ̀ rèé nípa ohun tá à ń sọ:

ÌTUMỌ̀ BÍBÉLÌ ÀTI IYE TÓ TI DỌ́WỌ́ ÀWỌN ÈÈYÀN

Bíbélì tí wọ́n tò pọ̀
  • 96.5% ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé gbogbo èèyàn tó wà láyé ló ní Bíbélì

  • 3,350 Èdè (LÓDINDI TÀBÍ LÁPÁ KAN)

  • 5,000,000,000 Èyí ni iye tí wọ́n ṣírò pé wọ́n ti tẹ̀ jáde, kò sí ìwé míì láyé yìí tí iye ẹ̀ tó bẹ́ẹ̀

MỌ PÚPỌ̀ SÍ I

LỌ SÓRÍ ÌKÀNNÌ WA, JW.ORG/YO. NÍBẸ̀

  • O lè ka Bíbélì lórí ìkànnì (ó wà ní èdè tó ju 260 lọ)

  • O lè wa Bíbélì jáde

  • O lè rí ohun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìbéèrè pàtàkì

  • O lè ka àwọn àpilẹ̀kọ nípa bí Bíbélì ṣe tún ayé ọ̀pọ̀ èèyàn ṣe

  • O lè kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì fúnra ẹ lórí ìkànnìa

  • O lè ní kẹ́nì kan wá kọ́ ẹ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

ÀWỌN BÍBÉLÌ TÍ ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ TI TẸ̀ JÁDE

ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ Ń TÚMỌ̀ BÍBÉLÌ, A SÌ Ń FÚN ÀWỌN ÈÈYÀN.

Díẹ̀ lára àwọn ìtumọ̀ Bíbélì tá a ti tẹ̀ jáde rèé:

  • The American Standard Version of 1901

  • The Bible in Living English, Byington

  • The Emphatic Diaglott

  • The King James Version

  • Revised Standard Version

  • Tischendorf’s New Testament

BÍBÉLÌ ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN

Àtẹ kan tó sọ nípa bí a ṣe tẹ Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun láti ọdún 1950 títí di 2020
  • 180+ Èdè (LÓDINDI TÀBÍ LÁPÁ KAN)

  • 227 MÍLÍỌ̀NÙ BÍBÉLÌ ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN TÓ TI JÁDE LÁTỌDÚN 1950

a Ní báyìí, ó wà ní èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Pótogí. A máa fi àwọn èdè mí ì kún un tó bá yá.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́