ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 10A
Ìjọsìn Mímọ́—Pa Dà Bọ̀ Sípò Díẹ̀díẹ̀
Bíi Ti Orí Ìwé
‘Ariwo tó dà bí ìgbà tí nǹkan ń rọ́ gììrì’
William Tyndale àtàwọn míì túmọ̀ Bíbélì sí èdè Gẹ̀ẹ́sì àtàwọn èdè míì
“Iṣan àti ẹran”
Charles T. Russell àtàwọn alábàákẹ́gbẹ́ rẹ̀ mú káwọn èèyàn lóye òtítọ́ Bíbélì
“Wọ́n wá di alààyè, wọ́n sì dìde dúró”
Lẹ́yìn táwọn èèyàn Jèhófà “di alààyè” lọ́dún 1919, wọ́n túbọ̀ tẹra mọ́ iṣẹ́ ìwàásù wọn