ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • rr ojú ìwé 56-57
  • “Ọmọ Èèyàn, Ṣé Ìwọ Náà Rí I?”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ọmọ Èèyàn, Ṣé Ìwọ Náà Rí I?”
  • Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ‘Wo Iṣẹ́ Ibi Tó Ń Ríni Lára Tí Wọ́n Ń Ṣe’
    Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Ẹ Ṣọra fun Gbogbo Oniruuru Ibọriṣa
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
  • Tùràrí Sísun Ǹjẹ́ Ó Lóhun Tó Ń Ṣe Nínú Ìjọsìn Tòótọ́?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • Wọ́n Pa Jerúsálẹ́mù Run
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
Àwọn Míì
Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
rr ojú ìwé 56-57

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 5A

“Ọmọ Èèyàn, Ṣé Ìwọ Náà Rí I?”

Bíi Ti Orí Ìwé

Ohun mẹ́rin tó ń kóni nírìíra tí Ìsíkíẹ́lì rí nínú àgbàlá àti tẹ́ńpìlì. (Ìsík. 8:​5-16)

Àwọn Júù apẹ̀yìndà ń forí balẹ̀, wọ́n ń jọ́sìn ère.

1. ÈRE OWÚ

Ìsíkíẹ́lì ń wo àgbàlá inú ní tẹ́ńpìlì, níbi tí àwọn àgbààgbà ti ń sun tùràrí sí àwọn òrìṣà tí wọ́n gbẹ́ sára ògiri.

2. ÀÁDỌ́RIN ÀGBÀÀGBÀ TÍ WỌ́N Ń SUN TÙRÀRÍ SÍ ÀWỌN ÒRÌṢÀ

Àwọn obìnrin tó ń sunkún torí ọlọ́run tí wọ́n ń pè ní Támúsì.

3. “ÀWỌN OBÌNRIN . . . TÍ WỌ́N Ń SUNKÚN TORÍ ỌLỌ́RUN TÍ WỌ́N Ń PÈ NÍ TÁMÚSÌ”

Ọkùnrin mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n tí wọ́n ń forí balẹ̀ fún oòrùn ní àgbàlá inú ní tẹ́ńpìlì.

4. ỌKÙNRIN MẸ́Ẹ̀Ẹ́DỌ́GBỌ̀N TÍ “WỌ́N Ń FORÍ BALẸ̀ FÚN OÒRÙN”

Pa dà sí orí 5, ìpínrọ̀ 7 sí 18

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́