Alábòójútó àyíká kan àti ìyàwó rẹ̀ lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn ní orílẹ̀-èdè Faransé, lọ́dún 1957
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Kí ni orúkọ Ọlọ́run?
Bíbélì: Sm 83:18
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe mọ̀ pé Jèhófà Ọlọ́run fẹ́ ká di ọ̀rẹ́ òun?
○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo la ṣe mọ̀ pé Jèhófà Ọlọ́run fẹ́ ká di ọ̀rẹ́ òun?
Bíbélì: Jak 4:8
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe lè di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run?
○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Báwo la ṣe lè di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run?
Bíbélì: Jo 17:3
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe lè sún mọ́ Ọlọ́run nígbà tá ò lè rí i?