January Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, January 2019 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ January 7-13 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 21-22 “Kí Ìfẹ́ Jèhófà Ṣẹ” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jèhófà Ló Bá Wa Tọ́ Àwọn Ọmọ Wa January 14-20 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 23-24 Wọ́n Fẹ̀sùn Kan Pọ́ọ̀lù Pé Alákòóbá Ni àti Pé Ó Ń Ru Ìdìtẹ̀ Sókè January 21-27 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 25-26 Pọ́ọ̀lù Ké Gbàjarè sí Késárì Ó sì Wàásù fún Ọba Hẹ́rọ́dù Àgírípà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Òfin Fìdí Iṣẹ́ Wa Múlẹ̀ ní Quebec January 28–February 3 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 27-28 Pọ́ọ̀lù Wọkọ̀ Ojú Omi Lọ sí Róòmù MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI “Pọ́ọ̀lù Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Ọlọ́run Ó sì Mọ́kànle”