ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 January ojú ìwé 5
  • Òfin Fìdí Iṣẹ́ Wa Múlẹ̀ ní Quebec

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Òfin Fìdí Iṣẹ́ Wa Múlẹ̀ ní Quebec
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ìjà Ogun Náà Kì í Ṣe Tiyín, Bí Kò Ṣe Ti Ọlọ́run”
    Jí!—2000
  • Mo Rí Ọ̀pọ̀ Ìbùkún Gbà Torí Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Tó Fi Àpẹẹrẹ Tó Dáa Lélẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2020
  • Àwọn Akéde Ìjọba Ọlọ́run Gbé Ọ̀rọ̀ Lọ Sílé Ẹjọ́
    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!
  • Jèhófà ni Ààbò àti Okun Mi
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 January ojú ìwé 5

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Òfin Fìdí Iṣẹ́ Wa Múlẹ̀ ní Quebec

Késárì, ọmọ ogun Róòmù kan, àti Pọ́ọ̀lù

Nígbà tí wọ́n ń gbẹ́jọ́ Pọ́ọ̀lù, ó ké gbàjarè sí Késárì. Bí Pọ́ọ̀lù ṣe lo ẹ̀tọ́ tó ní gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìbílẹ̀ Róòmù, ṣe ló fi àpẹẹrẹ lélẹ̀ fún wa lónìí. Wo fídíò náà Òfin Fìdí Iṣẹ́ Wa Múlẹ̀ ní Quebec, kó o sì wo bí àwọn ará wa ṣe fi òfin gbèjà iṣẹ́ ìhìn rere ní Quebec. Lẹ́yìn náà, dáhùn àwọn ìbéèrè yìí:

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórílẹ̀-èdè Quebec láwọn ọdún 1940; àkànṣe ìwé àṣàrò kúkúrú; arákùnrin kan ń sọ àsọyé lórí koríko nígbà ìfòfindè; Arákùnrin Aimé Boucher
  • Àwọn ìṣòro wo làwọn ará wa dojú kọ ní Quebec?

  • Àkànṣe ìwé àṣàrò kúkúrú wo ni wọ́n pín, kí ló sì yọrí sí?

  • Kí ló ṣẹlẹ̀ sí Arákùnrin Aimé Boucher?

  • Kí ni Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ti ilẹ̀ Kánádà ṣe fún Arákùnrin Boucher?

  • Ètò wo ló wà táwọn èèyàn kì í sábà lò, àmọ́ táwọn ará wa lò nílé ẹjọ́, kí ló sì yọrí sí?

  • Kí ló ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí àwọn àlùfáà ní kí àwọn ọlọ́pàá wá da ìpàdé rú?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́