ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 January ojú ìwé 6
  • January 28–February 3

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • January 28–February 3
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 January ojú ìwé 6

January 28–February 3

ÌṢE 27-28

  • Orin 129 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Pọ́ọ̀lù Wọkọ̀ Ojú Omi Lọ sí Róòmù”: (10 min.)

    • Iṣe 27:​23, 24​—Áńgẹ́lì kan sọ fún Pọ́ọ̀lù pé òun àtàwọn tó wà nínú ọkọ̀ ojú omi máa gúnlẹ̀ láyọ̀ (bt 208 ¶15)

    • Iṣe 28:​1, 2​—Ọkọ̀ ojú omi tí Pọ́ọ̀lù wọ̀ rì sí erékùṣù Málítà (bt 209 ¶18; 210 ¶21)

    • Iṣe 28:​16, 17​—Pọ́ọ̀lù dé Róòmù láyọ̀ (bt 213 ¶10)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Iṣe 27:9​—Kí ni “ààwẹ̀ [ọjọ́ ètùtù]”? (“ààwẹ̀ [ọjọ́ ètùtù]” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 27:9, nwtsty)

    • Iṣe 28:11​—Kí ló gbàfiyèsí nípa ère tó wà lórí ọkọ̀ yẹn? (“Àwọn Ọmọ Súúsì” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 28:11, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 27:​1-12 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 2)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 139 ¶16-17 (th ẹ̀kọ́ 3)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 103

  • “Pọ́ọ̀lù Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Ọlọ́run Ó sì Mọ́kànle”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà “Irin Ni A fi Ń Pọ́n Irin”​—Àyọlò. Rọ àwọn ará pé kí wọ́n lọ wo gbogbo fídíò náà látòkèdélẹ̀.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 2 ¶10-16

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 93 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́