ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 January ojú ìwé 4
  • Pọ́ọ̀lù Ké Gbàjarè sí Késárì Ó sì Wàásù fún Ọba Hẹ́rọ́dù Àgírípà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Pọ́ọ̀lù Ké Gbàjarè sí Késárì Ó sì Wàásù fún Ọba Hẹ́rọ́dù Àgírípà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Wọ́n Fẹ̀sùn Kan Pọ́ọ̀lù Pé Alákòóbá Ni àti Pé Ó Ń Ru Ìdìtẹ̀ Sókè
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 January ojú ìwé 4
Pọ́ọ̀lù dúró níwájú Ọba Hẹ́rọ́dù Àgírípà, ó sì wàásù fun un

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 25-26

Pọ́ọ̀lù Ké Gbàjarè sí Késárì Ó sì Wàásù fún Ọba Hẹ́rọ́dù Àgírípà

25:11; 26:​1-3, 28

Lóòótọ́ kò yẹ ká máa ṣàníyàn nípa ohun tá a máa sọ tí wọ́n bá mú wa wá “síwájú àwọn gómìnà àti àwọn ọba,” àmọ́ ó yẹ ká “wà ní ìmúratán” láti gbèjà ara wa níwájú ẹni tó bá béèrè nípa ìrètí wa. (Mt 10:18-20; 1Pe 3:15) Tí àwọn tó ń ta kò wá bá “fi àṣẹ àgbékalẹ̀ dáná ìjàngbọ̀n,” báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù?​—Sm 94:20.

  • A máa lo ẹ̀tọ́ wa lábẹ́ òfin láti gbèjà ìhìn rere.​—Iṣe 25:11

  • A máa ń bọ̀wọ̀ fún àwọn aláṣẹ tá a bá ń bá wọn sọ̀rọ̀.​—Iṣe 26:​2, 3

  • Tó bá yẹ bẹ́ẹ̀, a máa sọ bí ìhìn rere náà ṣe ran àwa àtàwọn míì lọ́wọ́.​—Iṣe 26:​11-20

Arábìnrin kan dúró níwájú adájọ́ kan, ó sì wàásù fun un

Ṣé o ti ronú lórí ohun tó o lè sọ táwọn kan bá bi ẹ́ nípa àwọn ohun tó o gbà gbọ́?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́