ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 January ojú ìwé 4
  • January 21-27

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • January 21-27
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 January ojú ìwé 4

January 21-27

ÌṢE 25-26

  • Orin 73 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Pọ́ọ̀lù Ké Gbàjarè sí Késárì Ó sì Wàásù fún Ọba Hẹ́rọ́dù Àgírípà”: (10 min.)

    • Iṣe 25:11​—Pọ́ọ̀lù lo ẹ̀tọ́ tó ní láti ké gbàjarè sí Késárì (bt 198 ¶6)

    • Iṣe 26:​1-3​—Pọ́ọ̀lù fọgbọ́n gbèjà òtítọ́ lọ́nà tó dára níwájú Ọba Hẹ́rọ́dù Àgírípà (bt 198-201 ¶10-16)

    • Iṣe 26:28​—Ìwàásù Pọ́ọ̀lù wọ ọba lọ́kàn (bt 202 ¶18)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Iṣe 26:14​—Kí ni ọ̀pá kẹ́sẹ́? (“títàpá sí ọ̀pá kẹ́sẹ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 26:14, nwtsty; “Ọ̀pá Kẹ́sẹ́” nwtstg)

    • Iṣe 26:27​—Kí nìdí tó fi ṣòro fún Ọba Àgírípà láti fèsì nígbà tí Pọ́ọ̀lù béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ bóyá ó gba àwọn wòlíì gbọ́? (w03 11/15 16-17 ¶14)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 25:​1-12 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 2)

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fi ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni han onílé. (th ẹ̀kọ́ 3)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 38

  • “Òfin Fìdí Iṣẹ́ Wa Múlẹ̀ ní Quebec”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 2 ¶1-9

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 122 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́