ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 January ojú ìwé 3
  • Wọ́n Fẹ̀sùn Kan Pọ́ọ̀lù Pé Alákòóbá Ni àti Pé Ó Ń Ru Ìdìtẹ̀ Sókè

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wọ́n Fẹ̀sùn Kan Pọ́ọ̀lù Pé Alákòóbá Ni àti Pé Ó Ń Ru Ìdìtẹ̀ Sókè
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Pọ́ọ̀lù Ké Gbàjarè sí Késárì Ó sì Wàásù fún Ọba Hẹ́rọ́dù Àgírípà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 January ojú ìwé 3
Ìbátan Pọ́ọ̀lù ń bá ológun kan sọ̀rọ̀

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 23-24

Wọ́n Fẹ̀sùn Kan Pọ́ọ̀lù Pé Alákòóbá Ni àti Pé Ó Ń Ru Ìdìtẹ̀ Sókè

23:​12, 16; 24:​2, 5, 6, 10-21

Àwọn Júù tó wà ní Jerúsálẹ́mù “fi ègún de ara wọn” pé àwọn gbọ́dọ̀ pa Pọ́ọ̀lù. (Iṣe 23:12) Àmọ́, ìfẹ́ Jèhófà ni pé kí Pọ́ọ̀lù lọ wàásù ní Róòmù. (Iṣe 23:11) Nígbà tí ìbátan Pọ́ọ̀lù kan gbọ́ pé wọ́n fẹ́ pa á, ó lọ sọ fún Pọ́ọ̀lù, ìyẹn ni kò jẹ́ kí wọ́n rí Pọ́ọ̀lù pa. (Iṣe 23:16) Kí ni ìtàn yìí kọ́ ẹ nípa . . .

  • ohunkóhun táwọn èèyàn bá ṣe láti ta ko ohun tí Ọlọ́run ní lọ́kàn?

  • ohun tí Ọlọ́run lè ṣe láti ràn wá lọ́wọ́?

  • ìgboyà?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́