ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • yb17 ojú ìwé 82-83
  • Jọ́jíà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jọ́jíà
  • Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2017
Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2017
yb17 ojú ìwé 82-83
Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan ń wàásù fún ọkùnrin kan ní àgbègbè olókè kan ní Jọ́jíà

Jọ́jíà

BÍ Ọ̀RỌ̀ Ìjọba Ọlọ́run ṣe tàn kálẹ̀ lórílẹ̀-èdè Jọ́jíà bá ohun tí Jésù sọ mu gẹ́lẹ́ nínú àpèjúwe ìwúkàrà tó fara pa mọ́ sínú ìyẹ̀fun. (Mát. 13:33) Ó kọ́kọ́ dà bíi pé ẹ̀kọ́ òtítọ́ ò fi bẹ́ẹ̀ méso jáde lórílẹ̀-èdè náà, bí ìgbà tí ìwúkàrà fara pa mọ́ sínú ìyẹ̀fun, àmọ́ nígbà tó yá, ẹ̀kọ́ òtítọ́ délé dóko, ó sì yí ìgbésí ayé ọ̀pọ̀ èèyàn pa dà.

Ka àwọn ìtàn amóríyá, tó wọni lọ́kàn nípa bí àwọn èèyàn Ọlọ́run ní Jọ́jíà ṣe fi hàn pé wọ́n ní ìfẹ́ àti ìgbàgbọ́, pé wọ́n jẹ́ adúróṣinṣin, wọ́n lo ìdánúṣe àti pé wọ́n ní ìgboyà ní ‘àsìkò tí ó rọgbọ àti ní àsìkò tí ó kún fún ìdààmú.’​—2 Tím. 4:2.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́