Jòhánù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bákan náà, kò sí èèyàn kankan tó tíì gòkè lọ sọ́run+ àfi ẹni tó sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run,+ ìyẹn Ọmọ èèyàn. Hébérù 11:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ìgbàgbọ́ mú ká ṣí Énọ́kù+ nípò pa dà kó má bàa rí ikú, a ò sì rí i níbì kankan torí pé Ọlọ́run ti ṣí i nípò pa dà;+ torí ká tó ṣí i nípò pa dà, ó rí ẹ̀rí pé ó ti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run dáadáa.
13 Bákan náà, kò sí èèyàn kankan tó tíì gòkè lọ sọ́run+ àfi ẹni tó sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run,+ ìyẹn Ọmọ èèyàn.
5 Ìgbàgbọ́ mú ká ṣí Énọ́kù+ nípò pa dà kó má bàa rí ikú, a ò sì rí i níbì kankan torí pé Ọlọ́run ti ṣí i nípò pa dà;+ torí ká tó ṣí i nípò pa dà, ó rí ẹ̀rí pé ó ti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run dáadáa.