Sáàmù 78:40, 41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Ẹ wo iye ìgbà tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i ní aginjù,+Tí wọ́n sì bà á nínú jẹ́ ní aṣálẹ̀!+ 41 Léraléra ni wọ́n dán Ọlọ́run wò,+Wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá* Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì.
40 Ẹ wo iye ìgbà tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i ní aginjù,+Tí wọ́n sì bà á nínú jẹ́ ní aṣálẹ̀!+ 41 Léraléra ni wọ́n dán Ọlọ́run wò,+Wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá* Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì.