Jẹ́nẹ́sísì 1:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Jẹ́ ká+ dá èèyàn ní àwòrán wa,+ kí wọ́n jọ wá,+ kí wọ́n sì máa jọba lórí àwọn ẹja inú òkun, àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run, àwọn ẹran ọ̀sìn, lórí gbogbo ayé àti lórí gbogbo ẹran tó ń rákò tó sì ń rìn lórí ilẹ̀.”+ Jémíìsì 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí àwọn èèyàn máa ń kápá gbogbo ẹran inú igbó àti ẹyẹ àti ẹran tó ń fàyà fà* àti ẹ̀dá inú òkun, wọ́n sì ti kápá wọn.
26 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Jẹ́ ká+ dá èèyàn ní àwòrán wa,+ kí wọ́n jọ wá,+ kí wọ́n sì máa jọba lórí àwọn ẹja inú òkun, àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run, àwọn ẹran ọ̀sìn, lórí gbogbo ayé àti lórí gbogbo ẹran tó ń rákò tó sì ń rìn lórí ilẹ̀.”+
7 Torí àwọn èèyàn máa ń kápá gbogbo ẹran inú igbó àti ẹyẹ àti ẹran tó ń fàyà fà* àti ẹ̀dá inú òkun, wọ́n sì ti kápá wọn.