2 Ó wá sọ pé: “Jọ̀ọ́, mú ọmọ rẹ, ọmọ rẹ kan ṣoṣo tí o nífẹ̀ẹ́ gidigidi,+ ìyẹn Ísákì,+ kí o sì lọ sí ilẹ̀ Moráyà,+ kí o fi rú ẹbọ sísun níbẹ̀ lórí ọ̀kan nínú àwọn òkè tí màá fi hàn ọ́.”
3Nígbà náà, Sólómọ́nì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ilé Jèhófà+ sí Jerúsálẹ́mù lórí Òkè Moráyà,+ níbi tí Jèhófà ti fara han Dáfídì bàbá rẹ̀,+ ibẹ̀ ni Dáfídì ṣètò sílẹ̀ ní ibi ìpakà Ọ́nánì+ ará Jébúsì.