Jẹ́nẹ́sísì 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 O ò ní jẹ́ Ábúrámù* mọ́; orúkọ rẹ yóò di Ábúráhámù,* torí màá mú kí o di bàbá ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè. Jẹ́nẹ́sísì 46:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àwọn ni ọmọkùnrin tí Líà bí fún Jékọ́bù ní Padani-árámù, pẹ̀lú Dínà+ ọmọbìnrin rẹ̀. Gbogbo àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin rẹ̀* jẹ́ mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33). Jẹ́nẹ́sísì 46:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àwọn ọmọ Réṣẹ́lì ìyàwó Jékọ́bù ni Jósẹ́fù+ àti Bẹ́ńjámínì.+ 1 Kíróníkà 2:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ nìyí: Rúbẹ́nì,+ Síméónì,+ Léfì,+ Júdà,+ Ísákà,+ Sébúlúnì,+ 2 Dánì,+ Jósẹ́fù,+ Bẹ́ńjámínì,+ Náfútálì,+ Gádì+ àti Áṣérì.+
15 Àwọn ni ọmọkùnrin tí Líà bí fún Jékọ́bù ní Padani-árámù, pẹ̀lú Dínà+ ọmọbìnrin rẹ̀. Gbogbo àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin rẹ̀* jẹ́ mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33).
2 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ nìyí: Rúbẹ́nì,+ Síméónì,+ Léfì,+ Júdà,+ Ísákà,+ Sébúlúnì,+ 2 Dánì,+ Jósẹ́fù,+ Bẹ́ńjámínì,+ Náfútálì,+ Gádì+ àti Áṣérì.+