-
Ẹ́kísódù 37:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Lẹ́yìn náà, ó fi ògidì wúrà ṣe àwọn ohun èlò tó wà lórí tábìlì—àwọn abọ́ ìjẹun rẹ̀, àwọn ife rẹ̀, àwọn abọ́ rẹ̀ àti àwọn ṣágo tí wọ́n á máa da ọrẹ ohun mímu látinú rẹ̀.+
-