Nọ́ńbà 16:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kórà+ ọmọ Ísárì,+ ọmọ Kóhátì,+ ọmọ Léfì+ wá gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú Dátánì àti Ábírámù, àwọn ọmọ Élíábù+ pẹ̀lú Ónì ọmọ Péléétì, àwọn ọmọ Rúbẹ́nì.+ Nọ́ńbà 16:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ilẹ̀ sì lanu,* ó gbé wọn mì pẹ̀lú agbo ilé wọn àti gbogbo àwọn èèyàn Kórà+ pẹ̀lú gbogbo ẹrù wọn. Nọ́ńbà 26:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ilẹ̀ lanu,* ó sì gbé wọn mì. Ní ti Kórà, òun àtàwọn tó ń tì í lẹ́yìn kú nígbà tí iná jó igba ó lé àádọ́ta (250) ọkùnrin+ run. Wọ́n wá di àpẹẹrẹ tó jẹ́ ìkìlọ̀.+
16 Kórà+ ọmọ Ísárì,+ ọmọ Kóhátì,+ ọmọ Léfì+ wá gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú Dátánì àti Ábírámù, àwọn ọmọ Élíábù+ pẹ̀lú Ónì ọmọ Péléétì, àwọn ọmọ Rúbẹ́nì.+
10 Ilẹ̀ lanu,* ó sì gbé wọn mì. Ní ti Kórà, òun àtàwọn tó ń tì í lẹ́yìn kú nígbà tí iná jó igba ó lé àádọ́ta (250) ọkùnrin+ run. Wọ́n wá di àpẹẹrẹ tó jẹ́ ìkìlọ̀.+